GBOLOHUN

Pry six

Akole:GBOLOHUN

 

KINI A NPE NI GBOLOHUN?Gbolohun ni akojopo oro ti eemile gbe jade lekan soso tabi gbolohun ni ipe de ti okun ti o si ni itunmo.

Orisirisi gbolohun ni o wa ninu ede yoruba lara won ni awon wonyii.

1.gbolohun ibeere

2.gbolohun alaye

3.gbolohun ase

4.gbolohun onibo

5.gbolohun alakanpo.

 

GBOLOHUN IBEERE:Gbolohun ibeere ni a fi nse ibeere ti sorosoro ba nsoro gbo fun olugbo ,gbolohun yii ni yoo lo lati fi beere oro bi apeere.NIBO NI O NLO?.

 

GBOLOHUN ALAYE

Gbolohun alaye ni a fi maa nse alaye ohun ti a ba feso fun eniyan bi apeere:INA NJO LEYIN KULE

 

GBOLOHUN ASE

Gbolohun ase ni a gi npase fun eniyan bi apeere:JOKO ,DIDE.

 

GBOLOHUN ONIBO

Gbolohun onibo ni gbolohun ti a fi ihun gbolohun miran bo laarin ,ki ole ni itunmo , kikun bi apeere:ILE TOBI —–ILE TI MOKO TOBI.

 

GBOLOHUN ALAKANPO

Gbolohun alakanpo ni gbolohun kan ati gbolohun miran ti a so papo bi apeere:PELU ,AMO abbl

 

Ise kilaasi

Daruko marun orisi gbolohun ki osi salaayr meta ninu re

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share