Class: Pry three
Subject: Yoruba Studies
Akole: akanlo ede ati itunmo re
- Se aya gbangba!
Itumo: ki eniyan doju ko isoro lai beru
- Ya apa!
Itumo: ki eniyan ma mọ itoju owo tabi ohun ti a fi owo ra
- Edun arinle!
Itumo: eni ti o ti lowo ri sugbon ti opa da rago tàbí kushe
- Fi aake kori!
Itumo: ki eniyan ko jale lati se nkan
- Fi ìgbà gba ga..
Itumo: idije,ki ẹniyan koju ara won lati dan agbara won woo
Akanlo ede ni ile Yoruba
Akanlo ede
Ise kilaasi
So itumo awon akanlo ede wonyii
- Se aya gbangba
- Edu arinle
- Fi ìgbà gba ga
- Ya apa
- Fi aake kori
Spread the Word, Share This!
Related