Onka ni ede yoruba lati ori ookan de ori ewaa

Date: Friday, 1st May, 2020.

Class: Pry one

Subject: Yoruba Studies

 

Akole: Onka ni ede yoruba lati ori ookan de ori ewaa.

 

1-ookan

2-Eeji

3-Eeta

4-Eerin

5-Aarun

6-Eefa

7-Eeje

8-Eejo

9-Eesan

10-Ewaa

 

Review work:

 

Kini oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba

 

1: 2- (a) Eerin (b) Eeji

2: 4- (a) Eefa. (b) Eerin

3: 1- (a) Ookan (b) Eeta

4: 3- (a) Aarun (b) Eeta

5: 5- (a) Eejo. (b) Aarun

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *