Àṣà Àti Ìṣe Yoruba
Yoruba dùn lasha, Yoruba dùn ni ìwà, Yoruba dùn ni èdè, oyin ni.
Ásà, ìwà, isẹ àti èdè Yorùbá jé èdè tí ó gbajugbaja nínú àwọn èdè ni orile ayé yí.
Àwọn Yorùbá ni wọ́n ní kí wọ́n wọ aṣọ kí ó sì dun wo lójú, kí wọ́n di irun orí ki o dabi ẹni pé adeda mo ní. Àwọn Yorùbá loni kí á soro kí a sì fà komu òkun ẹyọ. Kí a sọ ro kí ó kún fún ẹwà èdè.
Àwọn Yorùbá loni kí á kọrin kí òsì dùn gbó létí. Nípa orin kiko, àwọn ènìyàn pápá julọ ọmọ kaaro ojire, kólé gbàgbé àwọn akoni orin bí Bàbá Ayinla ọmọ wúrà, bàbà ambrose Kambel, Bàbà Fatai Rolling Dollars, Alahaji Ayinde Barrister àti bèbè lọ,.
Àwọn akorin wonyi tí fi orin ṣe ikilọ, ìbáwí, idaraya ẹni nínú dùn àti bèbè lọ. Àwọn akoni wonyi tí fi ona topo gba àṣà Yoruba ga larin àwa èdè àti eya tí ó wà lórí ilẹ̀ ayé yìí.
Kii se ni pá orin nìkan ni àwọn Yoruba fi gbaju gbaná laarin awọn eya toku, Nínú ọ̀rọ̀ sísọ kiasi mú ẹwà èdè jáde nimú rẹ, wọn gbìyànjú lọpọlọpọ.[mediator_tech]
Yoruba loni kí á pá òwe,, kíá ro Aroba tí ṣe Baba ìtàn. Àwọn Yorùbá loni kí á kini kí a sì ṣe aájò tàbí àlejò pelu rẹ.
Òrìsà Ṣíṣe
Tí aba nsọ nípa àṣà, akole masalai menu bá òrìṣà sise ni ile Yoruba. Òrìṣà sise je ki Yoruba gbajugbaja larin awọn ẹ̀yà orile ayé. Yorùbá gbajumo tó bẹ tí wọn nfi wá yangàn laarin awọn aláwò funfun