OSE KEJO
EKA ISE: EDE
AKOLE ISE:
OSE KEJO
EKA ISE: EDE
AKOLE ISE: ONKA – OOKALELAADOTA DE OGORUN-UN (51-100).
51 |
Ookan le laadota |
50+1=51 |
52 |
Eeji le laadota |
50+2=52 |
53 |
Eeta le laadota |
50+3=53 |
54 |
Eerin le laadota |
50+4=54 |
55 |
Aarun din logota |
60-5=55 |
56 |
Eerin din logota |
60-4=56 |
57 |
Eeta din logota |
60-3=57 |
58 |
Eeji din logota |
60-2=58 |
59 |
Ookan din logota |
60-1=59 |
60 |
Ogota |
60 |
61 |
Ookan le logota |
60+1=61 |
62 |
Eeji le logota |
60+2=62 |
63 |
Eeta le logota |
60+3=63 |
64 |
Eerin le logota |
60+4=64 |
65 |
Aarun din laadorin |
70-5=65 |
66 |
Eerin din laadorin |
70-4=66 |
67 |
Eeta din laadorin |
70-3=67 |
68 |
Eeji din laadorin |
70-2=68 |
69 |
Ookan din laadorin |
70-1=69 |
70 |
Aadorin |
70 |
71 |
Ookan le laadorin |
70+1=71 |
72 |
Eeji le laadorin |
70+2=72 |
73 |
Eeta le laadorin |
70+3=73 |
74 |
Eerin le laadorin |
70+4=74 |
75 |
Aarun din logorin |
80-5=75 |
76 |
Eerin din logorin |
80-4=76 |
77 |
Eeta din logorin |
80-3=77 |
78 |
Eeji din logorin |
80-2=78 |
79 |
Ookan din logorin |
80-1=79 |
80 |
Ogorin |
80 |
81 |
Ookan le logorin |
80+1=81 |
82 |
Eeji le logorin |
80+2=82 |
83 |
Eeta le logorin |
80+3=83 |
84 |
Eerin le logorin |
80+4=84 |
85 |
Aarun din laa dorun-un |
90-5=85 |
86 |
Eerin din laa dorun-un |
90-4=86 |
87 |
Eeta din laa dorun-un |
90-3=87 |
88 |
Eeji din laa dorun-un |
90-2=88 |
89 |
Ookan din laa dorun-un |
90-1=89 |
90 |
Aadorun-un |
90 |
91 |
Ooksn le laa dorun-un |
90+1=91 |
92 |
Eeji le laa dorun-un |
90+2=92 |
93 |
Eeta le laa dorun-un |
90+3=93 |
94 |
Eerin le laa dorun-un |
90+4=94 |
95 |
Aarun din logorun-un |
100-5=95 |
96 |
Eerin din logorun-un |
100-4=96 |
97 |
Eeta din logorun-un |
100-3=97 |
98 |
Eeji din logorun-un |
100-2=98 |
99 |
Ookan din logorun-un |
100-1=99 |
100 |
Ogorun-un |
100 |
EKA ISE: ASA
AKOLE ISE: ASA ATI OHUN ELO ISOMOLORUKO.
Asa isomoloruko je ona ti a n gba fun omo tuntun ni oruko ti yoo maa je titi lae ni ile Yoruba.
Gbogbo ohun ti olodumare da saye lo ni oruko. oniruuru ohun-elo tabi eronja ni Yoruba si maa n lo ni gba Ikomojade . Ojo kefa ni Yoruba n so omo loruko, I ba se omokurin tabi omobinrin tabi ibeji sugbon ni ibo miiran , ojo kesan-an ni won n so omokunrin lorunko, ojo keje ni ti obinrin ti awon ibeji ni ojo kejo.
Die lara ohun elo isomoloruko niyi,
Ohun elo |
Iwure/adura |
Obi |
Bibi lobi n biku danu, bibi lobi n baarun danu, obi a bi ibi aye re danu. |
Orogbo |
Orogbo maa n gbo saye ni, o o gbo o, wa a to, wa a gbo kejekeje, o ko ni gbo igbo iya. |
Oyin |
A kii foyin senu ka roju koko, oro bi oyin bi adun ko ni dagbere fun o o koni je ikoso laye. |
Oti |
Oti kii ti, oko ni ti laye bee ni oti kii te, o ko ni t e |
Epo pupa |
Epo ni iroju obe, aye re a roju. |
Iyo |
Iyo nii mu obe dun, iwo ni o maa mu inu awon obi re dun. |
Ataare |
Ataare kii bimo tire laabo, fofo ni le ataare n kun, oye re a kun fomo. |
Aadun |
adun adun ni a n ba nile aadun, ibaje oni wole to o. |
Ireke |
A kii ba kikan ninu ireke, ikoro ko ni wo aye re lae, aye re yoo dun |
Omi tutu |
Omi la buwe, omi la bumu enikan kii ba omi sota,koo mu to
Ko ni gbodi ninu re o
Ko si ni sa pa o lori……… |
EKA ISE: LITIRESO
AKOLE ISE: AWON LITIRESO APILEKO ITAN AROSO – KIKA IW E TI IJOBA YAN
Igbelewon:
- Kin ni asa isomoloruko?
- Ko ohun elo isomoloruko marun un ki o si so bi a se n fi wure fun omo tuntun
- Ko onka lati aadota de ogoorun
Ise asetilewa:Ise sise inu Yoruba Akayege for jssone

Spread the Word, Share This!
Related
About The Author
Edu Delight Tutors
Am a dedicated educator with a passion for learning and a keen interest in technology. I believe that technology can revolutionize education and am committed to creating an online hub of knowledge, inspiration, and growth for both educators and students. Welcome to Edu Delight Tutors, where learning knows no boundaries.