Third Term Examinations Primary 5 Yoruba
THIRD TERM
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KARUN-UN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Aroko alariyanjiyan maa n da lori ______ (a) ise sise (b) iyan jija (d) ija jija
- Apeere oro oruko alaiseeka ni____(a) iyo (b) aga (d oluko
- Eniyan meloo ni o maa n ta ayo? (a) eniyan kan (b) eniyan meji (d) eniyan mewa
- Kini itumo foju lounje> (a) woran (b) gba oju mogi (d) foju
- Ise ni ____ise (a) oogun (b) bata (d) igo
- ____je apeere is ajumose (a) ona yiye (b) dida ilu ru (d) ole jija
- Omo ayo meloo ni o maa n wa ninu iho opon ayo kookan? (a) mefa (b) merin (d) meta
- ____je apeere oro aropo oruko (a) Jide (b) Awa (d) Aja
- Alaafin ni Oba ilu _____(a) Oyo (b) Oye (d) Oyan
- Ipinle meloo ni a ti lee ri aafin awon Oba alade ile Yoruba (a) meje (b) mefa (d) mejo
- Omo ayo meloo ni o wa ninu opon ayo lapapo? (a) Eejidinlaadota (b) Eejidinlogoji (d) (d) Ookanlelogun
- Kini owe wa fun? (a) ikilo (b) itanje (d) ise iyanu
- Anfaani ere ayo ni wipe , o maa n ____(a) je ki eniyan mo isiro (b) o maa n da opolo eniyan ru (d) o maa n dekun iba
- Apeere oro oruko aseeka ni ____(a) Tabili (b) suga (d) oyin
- “Juba ehoro” tumo si ___(a) salo (b) subu (d) sun
- Osu meloo ni o wa ninu odun? (a) osu meta (b) osu meji (d) osu mejila
- Ohun elo fun oge sise ni (a) alubosa (b) laali (d) Karosini
- Apeere ounje ile Yoruba ni ___(a) amala (b) semo (d) indomi
- Apeere oro oruko eran ko ni ___(a) pako (b) ewure (d) Amuga
- Tani olori ilu? (a) oluko (b) olopa (d) oba
- Aleebu ere ayo ni ___ (a) o maa n fi akoko sofo (b) o maa bu kun ewa wa (d) omaa n je ki ori pe
- Ipinle wo ni Ikeja wa? (a) ipinle oyo (b) ipinle eko (d) ipinle osun
- Orisii ise meloo ni a menuba ninu eko wa? (a) mefa (b) marun-un (d) merin
- Irinse agbe ni (a) oko (b) pakute (d) ibon
- Orisii agbe meloo ni o wa ___(a) meji (b) mefa (d) merin
- ____ ni o maa n ro ibon (a) ode (b) alagbede (d) akope
- Kini oruko ti a n pe awon onilu? (a) Ayan (b) olugbon (d) areas
- ____ni o maa n lo oko (a) ode (b) akope (d) agbe
- Ode ati ____ni o maa n to ofa (a) jagunjagun (b) onilu (d) agbe
- Ohun elo idana wo ni a maa fi n gbadura fun oko ati iyawo pe, won yoo bi omo pupo? (a) isu (b) iyo (D) ataare
IPIN KEJI: Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
- Ko apeere oro-oruko aseeka marun-un
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________
- Ko apeere oro-oruko alaiseeka marun-un
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________
- so oruko ilu awon oba alade wonyi
- ooni – ___________________________ii. Deji – ___________________________
iii. Oba – ___________________________iv. Olubadan -__________________________
- Timi – ___________________________vi. Ataoja – ___________________________
vii. Ewi – __________________________ viii. Alake – _________________________
- Osemowe- _______________________x. Emia – _____________________________
- So ona marun ti awon okunrin ile Yoruba n gba se oge
- ____________________________________ ii. ___________________________________
iii. ___________________________________iv. ___________________________________
- ____________________________________