YORÙBÁ PRIMARY 3 FIRST TERM EXAMINATION
FIRST TERM EXAMINATION 2021/2022
CLASS: PRIMARY 3
SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:………………………………………………………
EWI: IBAWI
E dake je je je
Omo ile eko, e gbohun enun mi,
E je nkorin ara si yin leti
Bee romo ile eko
Ti-nsojika
Ti-nwarun-unki
To tun nkotiikun soro agba
IBEERE:
1.) Arofo yii nba omo ________________ wi (a) ile-eko (b) ile-ise
2.) __________ to gbo baawi nii deni _________ leyin ola (a) iya, lile (b) omo, giga
3.) Omo to gbo ____________ nii fi __________ sese rin (a) ibawi, moto (b) iya, keke
4.) Eko ndi _______________ fomo to gbo ibawi (a) iyan (b) deko
5.) Ero ____________ ni gbogbo omo ti (a) eyin lawujo (b) iwaju nita
HUWA IMOORE SI OBI RE:
Adan dori kodo
O nwose eye
E je ka ronu wo
Ka mo baye ti n lo
Kamohun ti njele nile, loko ati nibi gbogbo
IBEERE:
1.) _________________ dori kodo (a) Adan (b) Asa
2.) O nwose ________________ (a) Eran (b) Eye
3.) E toju awon _______________ (a) Obi (b) ore
4.) Eyin _________________ gbogbo (a) agba (b) omode
5.) ___________ yii ko to rara (a) iwa (b) oro
ITOJU ARA
1.) Ojoojumo ni _____________ nfo eyin re (a) Ade (b) Sola
2.) A we gbogbo ___________ da saka (a) ese (b) ara
3.) Maa ______________ rira laaye (a) gbeyin (b) irun
4.) ___________ ti ngbabe eekanna ko kere (a) aisan (b) arun
5.) Yera fun wa _______________ patapata (a) obun (b) eso
IWE KIKA: AINA
i.) ____________ npa Aina (a) Ebi (b) Iya
ii.) Aina to __________ re lo (a) baba (b) iya
iii.) O dahun pe, oun fe je ____________ (a) eba (b) egbo
iv.) Aina fi obe ________ pelu ________ je eba naa (a) ewedu, isapa (b) efo, egusi
v.) Aina ____________ o si dupe lowo iya re (a) Kunle (b) duro
YORUBA LANGUAGE THIRD TERM PRIMARY 1 , 2 , 3, 4, 5 AND 6
YORUBA LANGUAGE PRIMARY 3 FIRST TERM EXAMINATION
.