Alifabeeti Èdè Yorùbá Primary 3

Àwọn wọ̀nyí ni leta tí ó wà nínú èdè alifabeeti Èdè Yorùbá

À B D E Ẹ F G GB H I J K L M Ń Ó Ọ P R S Ṣ T U W Y

Gbogbo leta tí ó wàá nínú èdè alifabeeti Èdè Yorùbá jé marundin lọ gbon

 

Àwọn alifabeeti Èdè Yorùbá ni leta kékeré ni wonyi

à b d e è f g gb h I j k l m ń ó ọ p r s ṣ t u w y

Àwọn konsonanti tí ó wàá nínú èdè Yorùbá

B D F G GB H  J K L M Ń P R S Ṣ T W Y

Àwọn faweeli tí ó wà nínú èdè Yorùbá

A E Ẹ I Ó Ọ U

 

 

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share