YORÙBÁ JSS 2 TÁÀMÙ KÌN-ÍN-NÍ
ÕSÊ | ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ | ÀMÚŚE IŚË |
1. | ÈDÈ: Sílébù Èdè Yorùbá ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì sílébù . 2. Ìhun sílébù (F, KF, Kos (N) 3. Pípín õrõ sí sílébù | OLÙKÖ 1. Sô oríkì sílébù 2. Śe àlàyé ìhun sílébù 3. Sç õpõlôpõ àpççrç pínpín õrõ sí sílébù sójú pátákó AKËKÕÖ 1. Têtì sí àlàyé olùkö 2. Śe àpççrç pípín õrõ sí sílébù fúnra rê 3. Kô ohun tí olùkö kô saju pátákó sínú ìwé OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI Pátákó ìkõwé. |
2. | ÀŚÀ: Êsìn Ìbílê Yorùbá ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Pàtàkì Êsìn Láwùjô Yorùbá 2. Ìgbàgbö Àti Èrò Àwôn Yorùbá Nípa Olódùmarè 3. Ipò Olódùmarè 4. Òrìśà Ilê Yorùbá 5. Êsìn òde òní: * Mùsùlùmí * Ômôlëyìn Jésù | OLÙKÖ 1. Śe àlàyé ipa ti êsìn ń kó láwùjô 2. Śe àlàyé ipò Olódùmarè nínú êsìn 3. Śàlàyé nípa àwôn òrìśà ilê Yorùbá àti bí a ti ń sìn wön. 4. Śe àlàyé àjôśe àárin àwôn çlësìn ìbílê, Mùsùlùmí àti Ômôlëyìn Jésú AKËKÕÖ 1. Sô ohun ti wön mõ nípa êsìn ìbílê Yorùbá àti êsìn ìgbàlódé 2. Jíròrò nípa àjôśe Olódùmarè, àwôn òrìśà àti olùsìn wôn. 3. Jíròrò lórí ìjà êsìn àti bí a śe lè dékun rê. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Àwòrán àwôn çlësìn oríśìí mëtêêtà níbi ìsìn. 2. Fídíò 3. Sinimá |
3. | LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn Ìwé Ìtàn Àròsô Ôlörõ Geere ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìsônísókí ìśêlê inú ìtàn abáyému 2. Êkö àti kókó õrõ tó súyô àti ìbáyému õrõ tó ń lô láwùjô, (bí àpççrç ipò/ ìpín obìnrin láwùjô, ìkôlura êsìn, ômôlúàbí, ìtöjú àyíká, ìlera, ààrùn éèdì/ rômôlöwölësê abbl) 3. Êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá 4. Ìlò èdè: (a) Ônà èdè – Àfiwé – òwe – Àkànlò èdè (b) Àwítúnwí – Ìfìrómõrísí – ìfohungbohùn abbl | OLÙKÖ 1. Śe ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí ìtàn náà dálé. 2. darí akëkõö láti tún ìtàn sô 3. Śe àlàyé lórí àwôn kókó-õrõ tó súyô àti ìbáyému wôn 4. Śe àlàyé nípa àwôn êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn 5. darí ìjíròrò nípa ìlò èdè nínú ìtàn náà. AKËKÕÖ 1. Ka ìwé náà 2. tún ìtàn náà sô ní sókí 3. jíròrò lórí kókó-õrõ inú ìwé náà àti ìbáyému wôn 4. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn. 5. Kópa nínú ìjíròrò lórí ìlò èdè. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé tí a yàn fún kíkà. 2. Àwòrán díê lára ìśêlê tó köni lëkõö nínú ìwé náà. |
4. | ÒÝKÀ: Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200). Kíka owó Náírà ÀKÓÓNÚ IŚË Òýkà láti Oókanléláàádöjô dé igba (151-200). Òýkà owó náírà b.a. náírà kan, náírà méjì, ogún náírà, ôgbõ náírà abbl. | OLÙKÖ 1. Tö àwôn akëkõö sönà láti ka òýkà – Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200). 2. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún. 3. Tö akëkõö sönà láti ka owó náírà pêlú òýkà Yorùbá. AKËKÕÖ 1. Ka òýkà láti Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200). 2. Dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkan 3. Dá owó náírà mõ àti bí a śe ń pè wön ní ìlànà òýkà Yorùbá 4. Kô òýkà tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí a kô òýkà láti Oókanléláàádöjô dé igba (151 – 200). 2. Káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí. 3. Owó náírà lóríśiríśi. |
5. | ÈDÈ: Oríśiríśi Gbólóhùn (Ìhun) ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì Gbólóhùn 2. Oríśiríśi Gbólóhùn * Alábödé * Alákànpõ * Oníbõ | OLÙKÖ 1. Fún gbólóhùn ní oríkì 2. Śe àlàyé ìhun õkõõkan àwôn oríśi gbólóhùn mëtêêta 3. Śe àpççrç õkõõkan irú àwôn gbólóhùn náà, kô wön sára pátákó, kí o sì kà wön fún akëkõö. 4. Darí akëkõö láti śe àwôn àpççrç mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö śe. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö nípa oríkì gbólóhùn àti ìhun õkõõkan àwôn oríśi gbólóhùn mëtêêta náà. 2. Da àwôn àpççrç tí olùkö kô sára pátákó kô sínú ìwé rç. 3. Pe àwôn gbólóhùn náà têlé olùkö 4. Śe àwôn àpççrç mìíràn yàtõ sí èyí tí olùkö śe. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
|
6. | ÈDÈ: Àmì Ohùn ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì àmì ohùn 2. Àlàyé lórí oríśi ohùn Yorùbá mëtêêta àti àmì wôn i. Ohùn àárin – (a kì í fi í hàn lórí õrõ) ii. Ohùn ìsàlê – iii. Ohùn òkè – 3. Fáwëlì àti oríśiríśi àmì ohùn kõõkan lórí fáwëlì kõõkan. Bí àpççrç: à, a, á, è, e, é, abbl 4. Àmì ohùn lórí õrõ onísílébù kan. B.a: bá, dà, kan abbl. | OLÙKÖ 1. Fún àmì ohùn ní oríkì 2. Śe àlàyé oríśi àmì ohùn mëtêêta 3. Kô àwôn fáwëlì pêlú ohùn orí wôn 4. Kô õrõ onísílébù kan àti ôlöpõ sílébù sára pátákó 5. pè wön fún akëkõö. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí oríkì àmì ohùn àti àwôn àmì mëtêêta. 2. Śe àdàkô fáwëlì àti àwôn õrõ tí olùkö kô. 3. Pe àwôn fáwëlì àti õrõ náà bí olùkö śe pè wön. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
|
7. | ÀŚÀ: Ìranra-çni-löwö ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Èsúsú 2. Àjô 3. Õwê 4. Àáró 5. Àrokodóko 6. Çgbë aláfôwösowöpõ òde òní. | OLÙKÖ 1. Śe àlàyé oríśiríśi àśà ìranra-çni-löwö àti àýfààní wôn 2. Śe àlàyé ipò àśà ìranra-çni-löwö nínú iśë àjùmõśe àti ôrõ-ajé 3. Darí akëkõö láti jíròrò lórí çgbë aláfôwösowöpõ. 4. Kó akëkõö lô sô ìdí çbu níbi tí wön ti ń jô fôwö-so-wöpõ śiśë AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö, sì śe àkôsílê kókó-õrõ bí ó ti yç. 2. Śe ìbéèrè lórí ohun tí kò bá yé e. 3. Kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí lórí çgbë aláfôwösowöpõ lóde òní 4. Têlé olùkö lô sí çbu láti lô wo àwôn òśìśë bí wön śe ń śiśë. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Fídíò 2. Fíìmù 3. Àwòrán |
8. | LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé eré-onítàn ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ibùdó ìtàn 2. Àhunpõ ìtàn 3. Àśà tó súyô 4. Kókó-õrõ 5. Ìfìwàwêdá 6. Ìlò èdè | OLÙKÖ 1. Darí akëkõö láti ka eré-onítàn náà. 2. Śe ìfáàrà lórí òýkõwé àti ohun tí eré náà dá lé. 3. Fa àwôn kókó õrõ yô 4. Jíròrò lórí êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn 5. Śe àfiwé ìśêlê inú ìtàn pêlú õrõ tó ń lô láwùjô. 6. Śe àlàyé lórí ìlò èdè 7. Darí ìśeré ní kíláásì, ìbá à jë ìran kan àbí méjì AKËKÕÖ 1. Ka eré-onítàn náà. 2. Ìjíròrò lórí ìśêlê tí wön ti gbö rí/ kà rí, tí ó fi ara pë èyí tí wön kà. 3. Fa êkö tí wön rí kö yô. 4. Töka sí oríśiríśi ìlò èdè 5. Jíròrò lórí àwôn êdá ìtàn àti ìfìwàwêdá wôn 6. Kópa nínú ìśeré tí olùkö darí ní kíláásì. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé ìròyìn 2. ìwé ìròyìn tí ìśêlê tó fara pë ti inú ìwé ti wáyé. 3. fíìmù tó bá eré mu (tí ó bá wà) 4. Aśô eré 5. Ohun èlò ìśeré |
9. | ÀŚÀ: Òýkà ôjö àti ośù ní ilê Yorùbá ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Òýkà àwôn ôjö tí ó wà nínú õsê. Ìtàn tí ó rõ mö ôn. Ôjö Ajé, Ìśëgun, Ôjörú, Ôjöbõ, Çtì, Àbámëta. 2. Àwôn ośù tí ó wà nínú ôdún: Śërë, Èrèlé, Erénà, Igbe, Èbìbí, Okúdù, Agçmô, Ògun, Ôwëwê, Õwàrà, Belu, Õpç. | OLÙKÖ 1. Śe àlàyé iye ôjö tí ó wà nínú õsê fún akëkõö 2. Kö akëkõö láti kô orin tí ó rõmö àwôn ôjö tó wà nínú õsê 3. Śe àlàyé iye ośù tí ó wà nínú ôdún fún akëkõö. 4. Darí akëkõö láti kô orin tí ó rõmö àwôn ośù tó wà nínú ôdún. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö nípa iye ôjö tí ó wà nínú õsê àti iye ośù tí ó wà nínú ôdún. 2. Kópa nínú orin tí olùkö darí ní kíláásì. 3. Śe àkôsílê ohun tí olùkö kô sójú pátákó sí inú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí a kô àwôn ôjö tí ó wà nínú õsê àti ośù tí ó wà nínú ôdún sí. 2. Káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn ôjö àti ośù sí |
10. | ÈDÈ: Aáyan Ògbufõ ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì aáyan ògbufõ 2. Ìtönisönà lórí bí a śe ń śe aáyan ògbufõ 3. Śíśe aáyan ògbufõ çlëyô õrõ láti èdè Gêësì sí Yorùbá 4. Túmõ gbólóhùn kéèkèèké láti èdè Gêësì sí Yorùbá. | OLÙKÖ 1. Fún aáyan ògbufõ ní oríkì. 2. Śe àlàyé bí a śe ń śe aáyan ògbufõ. 3. Śe aáyan ògbufõ çlëyô õrõ láti èdè Gêësì sí Yorùbá. 4. Túmõ gbólóhùn kéèkèèké láti èdè Gêësì sí Yorùbá AKËKÕÖ 1. Tëtí sí bí olùkö śe ń túmõ àwôn çyô õrõ àti gbólóhùn 2. Kô àwôn çyô õrõ àti àwôn gbólóhùn tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
|
11. | ÀŚÀ: Oúnjç Ilê Yorùbá ÀKÓÓNÚ IŚË
| OLÙKÖ 1. Sô oríkì oúnjç 2. Sô oríśiríśi oúnjç 3. Śe àlàyé bí a śe ń śe oúnjç kõõkan 4. Kô àwôn oúnjç tí ó bö sí ìsõrí kan náà sójú pátákó 5. Sõrõ lórí àýfààní oúnjç láti oko àti ewu oúnjç inú agolo AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö. 2. Sô èrò tiwôn lórí oúnjç 3. Kô ohun tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé. 4. Ya àtç tí olùkö yà sójú pátákó. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
|
12. | ÈDÈ: Gbólóhùn ÀKÓÓNÚ IŚË
| OLÙKÖ 1. Śe àlàyé ìhun õkõõkan àwôn oríśi gbólóhùn mëtêêta náà. 2. Da àwôn àpççrç tí olùkö kô sójú pátákó kô sínú ìwé rç 3. Pe àwôn gbólóhùn náà têlé olùkö 4. Śe àwôn àpççrç mìíràn yàtõ sí àwôn èyí tí olùkö ti śe OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI
|
13. | ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ | |
14. | ÌDÁNWÒ |