EWI AKOMOLEDE

OSE KÀRÚN 

AKORI EKO: EWI AKOMOLEDE

JE OLOGBON OMO

    A ko mi nifee

    Mo mo fee su

    A ko mi lror

    Mo moro atata I pe

    Awon agba lo ko mi ni samusamu

    Ti mot i menu ije

    Ife mi yato si teni ti n yinmu

    Oro mi yapa si tala taan toto

    Ipede mi mogbon dani

    Ife temi si ye eye to leti gidi

    Beeyan ba n soro ti o ni koko ninu

    Be e ba n pede ti o yeeyan

    Bi eni to n lu afefe lasan ni

    Ife mi kii se faditi eye rara

    Oro mi kii se fomugo eeyan

    Ologbon lo si le ye gidi

    Omoran lo si le modi oro

    Boo ba fe mfe mi ore

    Boo ba fe gbadun oro atata

    Je ologbon omo to dori eja mu

    Ma se jomugo atode to tiya pokii

Itunmo awon oro to ta koko ninu ewi

  1. Samusamu: didun tie nu maa n dun bi a ba nje nkan lenu
  2. Tala taa tontoto: tumo si omode ti o mo roo so se maa n pede
  3. Pokii: omo ti o ya alaigboran paraku (eni ti o ti baje ninu iwa buburu)

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share