Awọn Orukọ Amu Torun Wá Ní Ilé Yoruba

 

Class: Pry Six

 

Subject: Yoruba Studies

 

Akole:Awon omo amutorunwa

 

Awon omo wo ni ape ni omo amutorunwa?Omo amutorunwa ni awon omo ti a bi ni ipase ami iyanu ona ti won gba waye yato si bi a ti bi omo orisirisi ona ni won gba waye.

Awon omo amutorunwa naa ni awon wonyii

1.Ige–ige ni omo ti abi ti omu ese jade lati inu iya re,o le je okunrin tabi obinrin.

 

2.Ojo–ojo ni omolunrin ti o gbe iwo lorun lati inu iya re wa si aye.

 

Aina–Aina ni omobinrin ti o gbe iwo korun lati inu iya re wasi aye.

 

Dada–dada ni omo ti irun ori re takoko nigba ti ode ile aye.

 

Oke–oke ni omo ti o wa ninu apo lati inu iua re wa si ile aye.

 

Ajayi–ajayi ni omo ti o doju bole lati inu iya re wa si ile aye.

 

Ise kilaasi

 

Awon omo ni a noe ni omo amutorunwa?

 

Daruko marun ninu awon omo amutoruwa ki ose alaye meji ninu won.

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share