OGE SISE NI ILE YORUBA

 

Class: Pry six

Subject: Yoruba Studies

Akole: OGE SISE NI ILE YORUBA

 

Orisi risi ona ni angba se oge ni ile Yoruba, oge sise ni aye atijo ati oge sise ni aye ode oni

 

OGE SISE NI AYE ATIJO

Awon ona wonyii ni a ngba se oge ni ile yoruba ni aye atijo

 

1.OSUN KIKUN

Awa yoruba la ni asa osun kikun ni ikawo osun pupa, o dabi atike moju, inu igba ni osun nwa.iya omo tuntun akun osun si owo tabi ese asi kun fun omo re pelu.

 

  1. LAALI LILE

Awon hausa lo ni asa lali lile lati ibeere pepe a ko asa laali lile lati odo awon hausa,ewe igi kan ti amo si “ewe laali” ni a fin se laali lile. Agun papo pelu kaun adudu fafa ale si owo ati ese.

 

3.TIRO LILE

A maa nle tiro si oju omo ti aba ti we fun tan still okunein ati obinrin ni won le tiro fun,tiro lile dara pupo onko idoti oju,onje ki oju riran kedere si,onje ki oju gun rege.

 

  1. ETI LILU

Awon obinrin ni won maa ee eti lilu won yoo lu eti won mejeeji lati ko yere eti si,eyi ti ose ohun oso obinein.Awon eya miran maa lu eti ti won porogodo.

 

5.IRUN DIDI ATI ORI FIFA

Awon obinrin lo ni asa irun didi ni ikawo tabi ki won ko irun ori won,orisirisi ara ni awon iya wa fi irun won da

Awon oruko irun bi suku,patewo,kolese,ipako elede,panumo,ajanloso .

 

 

Ise kilaa si

 

  1. Awon woo ni oma di irun _(a)okunrin (b)obinrin

 

2.owo awon woo ni ati ko laali lile (a) hausa (b)igbo

 

3.awon woo ni oni asa eti lilu (a)okunrin (b)obinrin

 

4.awon woo ni ole le tiro

(a)okunrin ati obinrin (b)okunrin nikan

 

5.Tiro lile onje ki oju ___(a)riran kedere (b)ki oju fo

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *