YORUBA LANGUAGE PRIMARY 6
PRIMARY
6SUBJECT: YORUBA LANGUAGENAME:……………………………………………………………………………………IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON1.)Omo melo ni baba Dauda bi?
(a) meji (b) meta (d) okan (e) merin2.)Kini ise awon omo wonyii
(a) agbe (b) ode (d) ademu (e) akekoo3.)Eranko wo ni a kii je, ti
Dauda maa npa (a) Eye (b) Emo (d) Adan (e) Alangba4.)Kini o mu ki won re roba Dauda? (a) o fin pa eye (b) o fin pa adan(d) koje ki o koju si eko re (e)
o fi fo agbe emu5.)Kini Dauda fi ile agbon pe? (a) ile-eye (b) ile-eku (d) adan (e)
agbe-emuIWE KIKA: – LAMURIN YA WERE [mediator_tech][mediator_tech]
1.)Iru eniyan wo ni baba
Lamurin (a) oba (b) olowo (d) talaka (e)
ode2.)Ojo wo ni isele yii waye
ganan (a) ojo ose (b) ojo odun (d) ojo oja (e)
ojo ere3.)Kini Lamurin lose ni oko ni ojo naa(a) o lo wa igi (b) o lo he
ekuro (d) o lo sa obi (e) o lo wa isu4.)Kini o mu inu bi Lamurin(a) ko gbadun iwe naa(b) o ri
ewu re lorun elomiran(d) omi odo ko kaa
lara(e) orun wo o5.)Kini awon ero oja fi na
lamurin (a) ada (b) kumo (d) opa (e)
owoIWE KIKA: – WARA1.)Awon wo lo nse wara (a)
maluu (b) Fulani (d) bomubomu (e) kolobo2.)Ni akoko wo ni won maa
nbere ise wara sise (a) osan (b) iyale ta (d) owuro (e) oyanjo3.)Ara eranko wo ni won ti
nri wara (a) agbo (b) opije (d) ako maluu (e) abo maluu4.)Iru ewe wo ni won fin se
wara (a) ewe ope (b) ewe odan (d) ewe ibepe (e) ewe bomubomu5.)Ounje miran ti a maa nsebi wara ni _____ (a) isu (b)
eko (d) oka (e) ebaIKINI LENU ISE ATI IDAHUN
S/N Onise Ikini Idahun 1.) Alagbede 2.) Akope 3.) Babalawo 4.) Alaro 5.) Onidiri 6.) Awako 7.) Onisowo 8.) Alayo 9.) Ode 10.) Amokoko