PRIMARY 6 YORUBA LANGUAGE
NAME:…………………………………………………………………………………… IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON
- Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji (b) meta (d) okan (e) merin
- Kini ise awon omo wonyii (a) agbe (b) ode (d) ademu (e) akekoo
- Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye (b) Emo (d) Adan (e) Alangba
- Kini o mu ki won re roba Dauda? (a) o fin pa eye (b) o fin pa adan (d) koje ki o koju si eko re (e) o fi fo agbe emu
- Kini Dauda fi ile agbon pe? (a) ile-eye (b) ile-eku (d) adan (e) agbe-emu
IWE KIKA: – LAMURIN YA WERE
- Iru eniyan wo ni baba Lamurin (a) oba (b) olowo (d) talaka (e) ode
- Ojo wo ni isele yii waye ganan (a) ojo ose (b) ojo odun (d) ojo oja (e) ojo ere
- Kini Lamurin lose ni oko ni ojo naa (a) o lo wa igi (b) o lo he ekuro (d) o lo sa obi (e) o lo wa isu
- Kini o mu inu bi Lamurin (a) ko gbadun iwe naa (b) o ri ewu re lorun elomiran (d) omi odo ko kaa lara (e) orun wo o
- Kini awon ero oja fi na lamurin (a) ada (b) kumo (d) opa (e) owo
IWE KIKA: – WARA
- 1.) Awon wo lo nse wara (a) maluu (b) Fulani (d) bomubomu (e) kolobo
- Ni akoko wo ni won maa nbere ise wara sise (a) osan (b) iyale ta (d) owuro (e) oyanjo
- Ara eranko wo ni won ti nri wara (a) agbo (b) opije (d) ako maluu (e) abo maluu
- Iru ewe wo ni won fin se wara (a) ewe ope (b) ewe odan (d) ewe ibepe (e) ewe bomubomu
- Ounje miran ti a maa nsebi wara ni _____ (a) isu (b) eko (d) oka (e) eba
IKINI LENU ISE ATI IDAHUN
S/N | Onise | Ikini | Idahun |
1.) | Alagbede | ||
2.) | Akope | ||
3.) | Babalawo | ||
4.) | Alaro | ||
5.) | Onidiri | ||
6.) | Awako | ||
7.) | Onisowo | ||
8.) | Alayo | ||
9.) | Ode | ||
10.) | Amokoko |