YORÙBÁ JSS 2 TÁÀMÙ KEJÌ
ÕSÊ ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ ÀMÚŚE IŚË 1. LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé (Ewì Àpilêkô) ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àwôn ewì tó wà nínú ìwé tí a yàn 2. Kókó õrõ b.a. ìwà ènìyàn; àwôn êdá mìíràn tí kì í śe ènìyàn, õrõ tó ń lô láwùjô,, ìkôlura êsìn, ipò obìnrin, ètò ôrõ-ajé, ìśakô/ ìśabo – gbogbolômô, éèdì. Àkíyèsí: