Di awon alafo wonyii pelu awon leta ti o ye
FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023
CLASS: PRIMARY 1
SUBJECT: YORUBA
NAME:…………………………………………
- Di awon alafo wonyii pelu awon leta ti o ye:
A _______ D _____ E _____ G _____ I ______ J _____ L ____ N _____ O _____ R _____ S
- Kiini oruko nomba wonyii ni ede Yoruba :
- 3 – (a) Eeta (b) Arun-un
- 1 – (a) Eerin (b) Ookan
- 5 – (a) Arun-un (b) Eeji
- 2 – (a) Eeji (b) eefa
- 4 – (a) Eejo (b)Eerin
- Kiini oruko awon aworan wonyii:
- = (a) Ile (b) Ogba
- = (a) Owo, (b) Ese
- = (a) Oju (b) Eti
Ss
- = (a)Ododo (b) Ewe
- = (a) Igo (b) Agba
- Di awon oro wonyii pely leta ti o ye:
- IL___ (a) E (b) K
- OW___ (a) P (b) O
- OJ____ (a) K (b) U
- EW____ (a) E (b) T
- IG___ (a) M (b) O
FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023
CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- ORIN AKOMONIWA: OMO RERE
- Omo rere kii ___________ (a) puro (b) soro
- Omo rere kii ___________ (a) korin (b) jale
- Omo rere kii ___________ (a) seke (b) kawe
- Omo rere kii ___________ (a) kole (b) ja
- Omo rere kii ___________ (a) sole (b) sun
- IWA OMOLUABI: ITOJU ATI OORE SISE
- _______________ nse baba Aina (a) Aisan (b) Aarun
- _________________ wa kii. (a) Sola (b) Aina
- __________________ baba Aina nya die die (a) ese (b) Ara
- ___________________ su pupo (a) omi (b) ojo
- Iya _________________________ sa awon aso re si ita (a) Ade (b) Kemi
- IROYIN ATI ASOGBA
- Ile-eko mi dara: talo nsoro yii? (a) Tunde (b) Alaba
- Bee ni, sugbon ko dara to ile-eko tiwa: talo lo nsoro yii? (a) Alaba
(b) Tunde
- Wo o bi ododo se po yi kilaasi mi ka: talo nsoro yii? (a) Alaba (b) Tunde
- Igi ti o olew po ni ile eko temiju tire lo: talo nsoro yii? (a) Tunde
(b) Alaba
- Wo maluu ti baba mi ra, talo nsoro yii? (a) Alaba (b) Tunde
- AROFO IMOTOTO
- Fo ______________ re bi o baji (a) eyin (b) ese
- Gba __________________ re pelu (a) inu (b) ayika
- Ge _______________ re lasiko to ye (a) irun (b) imu
- Ge _______________ re to gun sobolo (a) eekanna (b) ori
- ______________ ti ngbe abe eekannaa ko kere (a) Aisan (b) Arun
FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023
CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- EWI: IBAWI
E dake je je je
Omo ile eko, e gbohun enun mi,
E je nkorin ara si yin leti
Bee romo ile eko
Ti nsojika
Ti nwarun-un ki
- Arofo yii nba omo ________________ wi (a) omo ile-eko (b) omo ile-ise
- __________ to gbo baawi ni deni _________ leyin ola (a) aya lile (b) omo giga
- Omo to gbo ____________ nii fi __________ sese rin (a) aye keke (b) ibawi moto
- Eko ndi _______________ fomo to gbo ibawi (a) iyan (b) deko
- Ero ____________ ni gbogbo omo ti nko ibawi (a) eyin lawujo (b) iwaju nita
- HUWA IMOORE SI OBI RE
Adan dori kodo
O nwose eye
Eje ka ronu wo
Ka mo baye tin lo
Ka mohun ti nsele nile, loko ati
Nibi gbogbo
- ____________________ dori kodo (a) Adan (b) Owiwi
- O nwose ___________________ (a) Eran (b) Eye
- E toju awon __________________ (a) ilu (b) obi
- Eyin _________________ gbogbo (a) omode (b) agba
- ___________ roko olowo (a) egbon (b) baba
- ITOJU ARA
- Ojoojumo ni _________ foe yin re (a) Ade (b) Kola
- A we gbogbo _________ re das aka (a) ese (b) ara
- ___________ re a mo nini ni gbogbo igba (a) aso (b) irun
- Ma __________ rira laaye (a) gbese (b) gbeyin
- ____________ ara a maa faisan (a) eeri (b) irun
- ITOJU ILE
- Ayika ile to doti maa nfa _______ (a) aisan (b) efori
- ________ kii se ore eniyan (a) arun (b) obun
- Ka maa gba ______ laaye (a) gbegbin (b) oorun
- ___________ nii wo aso _______ (a) omi igi (b) ina onida
- _________ lo yeni (a) obun (b) imototo
FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023
CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- IWE KIKA: ASIMU OLE
- _________ ni oruko oja ilu pokii (a) ikilo (b) oroorun (d) ayelu
- Ohun ti o se akoba fun pokii ni pe.
(a) o nra epa je (b) o ni ore pupo (d) o nlo si oja ayelu
- Eni ti o bu Pokii pe “Lanboroki, oju re jaa na” ni __________
(a) Ore Pokii kan (b) obi pokii (d) Aladugbo Pokii kan
- _______________ ni eni ti won fa omo ti o jale gan-an fun lati da seria fun-un
(a) olopaa (b) ore Pokii (d) ara oja ayelu
- Kini oruko Aladugbo Pokii ti omu-un pada sile? (a) Adigun (b) Alao (d) Akanni
- IWE KIKA: ADUBI ATI IYA RE
- Omo melo ni Iya Adubi bi? (a) omo meta (b) omo merin (d) omo kan
- Iru owo wo ni Awele nse (a) o nta eja (b) o nta isu (d) o nta ounje
- Ona wo ni Olorun gba pon Adunbi le? (a) Adubi ba iya re ta eja (b) Adubi gbe odo oyinbo oniwaasu (d) Adubi lo yunifasiti Ibadan
- Kiini o gbe Adubi de odo oyinbo oniwaasu
(a) O fe kawe sii (b) ko mo eniyan kankan (d) Ise omo odo
- Kini koje ki Awele le paaro aso bi awon elegbe re
(a) Ko feran oge (b) Aso won ni ilu won (d) Ere oja re ko po
- ILU ILE YORUBA
- ___________ lo ni ilu bata (a) onisango (b) olobatala
- Awon ____________ lo ni ilu ipese (a) ologun (b) Babalawo
- Awon ___________ lo ni ilu Agere (a) Elegun (b) ologun
- Awon ____________ lo ni ilu igbin (a) olobatala (b) elegun
- Awon ___________ lo ni ilu gbedu (a) olosa (b) oba ati ijoye
- OJU KO KURO
- Ohun to nfa oku kokoro ni ______ (a) iwa ibaje (b) afowofa (d) aini-itelorun
- Ohun ti o nbere ole ni ________ (a) afowofa (b) gbewiri (d) ojukokuro
- Ewo lo ye omo rere? (a) ole (b) afowora (d) itelorun
- Eba _______ to nse ojukokoro wi (a) odo (b) omode (d) arugbo
- Kini itumo agbewiri. (a) ole (b) ole (d) ika
FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023
CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- ERE IDARAYA
- Eniyan melon lo nta Ayo olopon. (a) meji (b) merin (d) meta
- Omo Ayo me lo ni o ngbe oju opon aypo lapopo. (a) merinla (b) mejilelogun (d) mejidinladota
- Apa ____________ ni a nta ayo si (a) osi(b) otun (d) eyin
- Awon ti o nduro woran nibi ere Ayo ni a npe ni _______ (a) onilaja ayo (b) oniduro ayo (d) osefe ayo
- Iru awo wo ni awo omo ayo. (a) awoeeru (b) awo eweko (d) awo pupa
- AKANLO EDE :
- Kini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo
(a) ko si epa mo (b) ko si atunse mo (d) epa ko si ninu oro
- Kini itumo akanlo ede yii: Edun arinle
(a) edun ti o nrin ni ile (b) edun ti o po ganan (d) eni ti o ti lowo ri, sugbon ti o pada raago
iii. Kini itumo akanlo ede yii: Fi aake kori: (a) ki eniyan ko jale lati se nnkan (b) ki eniyan ko jale (d) kin eniyan fi aake si ori
- Kini itumo akanlo ede yii : te oju aje mole (a) ya ole (b) ya ika (d) ya apa
- Kini itumo akanlo ede yii : se aya gbangba. (a) ki a ta aya siwaju (b) ki adoju ko isoro pelu aiberu ati aifoya (d) ki aya eniyan le
- OWE ILE YORUBA:
- Pari owe yii:- Agba kii nwa loja. (a) ki inu o bini (b) ko maa se lagbalagba (d) kori omo tuntun wo
- Pari owe yii:- obe ti bale ile kii nje: (a)ko dun ni (b) iyo ja ni (d) iyale ile kii nse
- Pari owe yii:- bi okete badagba: (a) a paje ni (b) omu omo e nii mu (d) asalo ni
- Pari owe yii:- Bomode ba mowo we. (a) aba agba jeun (b) owo e mo ni (d) ate siwaju si
- Pari owe yii:- Ile ti a fi ito mo. (a) adara sini (b) ategun a gbe lo (d) iri ni yoo wo
- ONKA NI EDE YOURIBA
- Kiini oruko nonba yii ni ede Yoruba: 55 (a) Arundinlogun (b) Arundinlogoji (d) Arundinlogota
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 70 (a) adota (b) Adorin (d) Ogorun
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 100 (a) Ogota (b) Ogorun (d) Ogoji
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 85 (a) Arundinladorun (b) Arundinlogoji (d) Arundinladota
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 110 (a) Ogorun (b) Ogota (d) Adofa
FIRST TERM EXAMINATION 2022/2023
CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA
NAME:………………………………………………………………………………
- IWE KIKA: IYI ISE SISE
- Ibo ni orisun gbogbo iwa ibaje? (a) Ile-eko (b) Inu oko (d) Odede
- Ewo ni kii se iwa ibaje ninu awon wonyii (a) ole (b) akikanju (d) imele
- Iwa Agbeke di awokose fun awon elegbere nitori _________
(a) iro pipa re (b) iwa awon obi re (d) iwa omoluabi re
- Iya Agbeke fun-un ni _________ ko to bere ile-eko
(a) Aso tuntun (b) imoran (d) Ounje to dara
- Bawo ni Agbeke se jere iwa re ni ile-eko
(a) Won na-an legbe (b) won fun-un nise se (d) won fun-un ni eko ofe
- IWE KIKA: IJAKO LERE
- Kini Ajao fe se nigba ti Alagba Alao pariwo pe, “omo naa niyi”?
(a) o fe fun won ni ehoro (b) o fe ba ehoro sare (d) o fe salo
- Won ko pa tie bo o, “tumo si pe”
(a) won jaa ni patie (b) won na-an daadaa (d) won fi iya je e
- Inu Alagba Alao dun nitori won _____ (a) bu Ajao (b) na Ajao (d) ko won jade
- ______ ti Alagba Alao lo ni o je ki won ri Ajao (a) ile-eko (b) ita (d) ogba
- Oga ile-eko se ileri fun Alagba Alao pe oun yoo ____
- sare pe awon obi (b) lo si ago olopaa (d) ba gbogbo awon akekoo soro
- LITIRESO: EWI OMOLUABI
- Ninu ewi yii, a rii pe, omoluabi maa n _____ (a) siwahu (b) soyaya (d) se wobia
- Ewi yii ko nipe, omoluabi a maa ______ (a) sepe (b) woso ti ko mo (d) jeun ni won-tunwon-si
- Omo ti yoo je asa mu tumo si _____ (a) omo ti yoo je ologbon (b) oruko re yoo maa je Asamu (d) yoo sa nnkan mu
- Akewi yii fe ki a je ________ (a) omoluabi (b) ole (d) gbewiri
- Ewi yii so pe:- “a-la-jewora ni _______ (a) gbewiri (b) ole (d) wobia
- ONKA NI EDE YORUBA
- Kiini oruko nonba yii ni ede Yoruba: 110 (a) Adofa (b) Ogorun (d) Ogota
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 100 (a) Ogorun (b) Ogota (d) Ogoji
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 150 (a) Ogorin (b) Ogorun (d) Adojo
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 90 (a) Adota (b) Ogoji (d) Adorun
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 60 (a) Ogoji (b) Ogbon (d) Ogota