MID TERM TEST FIRST TERM PRIMARY 4 YORUBA           

               CLASS: GRADE 4             SUBJECT: YORUBA            TIME:

IPILE KINNI 

  1. ________ Ni ohun ti ilu dundun wulo fun julo (a) ayeye (b) ogun (c) oosa
  2. Asiko ti Yoruba maa n lu lati fi se faaji ni (a) aaro kutukutu (b) osan gangan (c) leyin ise oojo 
  3. Oruko wo mi a mo awon ti won lu ilu si (a) ayan (b) babalawo (c) alariwo
  4. Oro miiran fun sinwin ni _____ (a) sin (b) sin iwin (c) ya werey
  5. Aiye n yi tumo si pe _______ (a) aye ko duro si oju kan mo nipase iwa igbalode lorisirisi (b) boolu ni aye (c) aye n pooyi

 

IPELE KEJI.

  1. Kini odun keresimesi ni ede geesi  
  2. Daruko awon ilu merin ni ile yoruba 
  3. Eniyan meloo ni o le lu ilu dundun 
  4. Kini owo kobe 
  5. Awon wo lo n gba owo kobe
  6. Kini aleebu owo kobe gbigba 

 

di alafo oro wonyi

  1. O __ U F E
  2. A G B __ N
  3. B __ B __
  4. I K __ Y I

 

DARUKO AWON ASA IGBALODE ORISIRISI MARUN TI AWON EWE IWONYI N DA

 

 

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share