YORUBA FIRST TERM EXAMINATION PRIMARY 3
NAME:
CLASS: PRIMARY 3
SUBJECT: Eko Ede Yoruba
Edahun ibeere yi.
- O __________ lati maa sere ni opopona. (a) dara (b) buru (c) gbadun
- _________ ni ibi ti oko maa n gba (a) opopona (b) yara (c) afefe
- O to lati wo ona daadaa ki a to koja (a) beeni (b) beeko
- Ibi akoko ti a gbodo wa ki a to koja ni owo __________ (a) otun (b) osi (c) eyin
- Ere asapajude le fa jamba oko. (a) beeni (b) beeko
- 30 __________ (a) Aadota (b) asasi (c) ogbon
- 40 __________ (a) Aadota (b) ogoji (c) ogbon
- 50 __________ (a) ogoji (b) ogbon (c) aadota
- Aropo ni ami metala kuro ninu ogoji, melo lo maa ku?
(a) metadinlogbon (b) mejelelogbon (c) ogun ati meji
- ____________ ni apeere ise owo. (a) aworan yiya (b) ole jija (c) iro pipa
- Ere talo wa ninu ogba naa je ere _____________ (a) agbalagba (b) eranko (c) omode
- Obi gbodo pese eko to ye koro fun awon omo. (a) beeni (b) beeko
- ____________ lo gbodo pese ounje, ile, abo ati Alafia fun omo (a) obi (b) omo (c) aja
Pin awon oro wonyi si silebu
- Aga = _____________ + _____________
- Agbada = ________ + ________ + ________
- Alo onitan maa nkoni logbon (a) beeni (b) beeko
- Apere alo onitan ni alo ijapa ati elede. (a) beeni (b) beeko
- _________ je apeere oun elo ninu yaara. (a) ijoko (b) beedi (c) mejeji
- _________ ni apeere iwa rere (a) jagidijagan (b) iro pipa (c) ibowo fagba
- Iwa rere ma ____________ (a) koya je eyan (b) fa ikorira fun eeyan (c) je ki won feran eyan.
Daruko awon akoni Yoruba laye atijo merin ti o mo.
- ________________
- ________________
- ________________
- ________________
- ________________
Ko iwa buburu meta ti a ko gbodo wu
- _________________________________________
- _________________________________________
- _________________________________________
Daruko orisi meji yara to wa ninu ile
- ___________________
- ___________________
YORUBA FIRST TERM EXAMINATION PRIMARY 4
YORUBA FIRST TERM EXAMINATION PRIMARY 1