3RD TERM EXAM QUESTIONS PRIMARY 6 YORUBA LANGUAGE
THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION
CLASS: PRIMARY 6 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………
AYEWO
- Kiini oruko oye Oba Ile-Ife (a) Ooni (b) Alaafin (d) Awujale
- Kiini oruko oye Oba ilu Oyo (a) Alaafin (b) Ooni (d) Soun
- Kiini itumo akanlo ede yii: Te oju aje mole
(a) Ja-ole (b) Ya-apa (d) salo
- Kiini itumo akanlo ede yii: Kan oju abe niko
(a) Ka soro pato si ibi ti oro wa (b) Ka fi abe kan eniyan niko (d) Ka fi abe fa ori eniyan
- Kiini itumo akanlo ede yii: Epa ko boro mo
(a) ko si epa ninu oro (b) Ko si atunse mo (d) Ko si ija mo
- Kiini awon ara abule se fun Ajala (a) won buu (b) won kii (d) won na-an
- Ajala maa nse _____ kiri abule (a) ijangbon (b) agidi (d) omoluabi
- Kiini oruko nomba yii ni ede Yoruba: 110 (a) Ogorun (b) Adofa (d) Ogoje
- Kiini oruko nomba yii ni eded Yoruba: 90 (a) Ogoji (b) Ogota (d) Adorun
- Tani Olodumare? (a) olodumare lo nse ika fun wa (b) Olodumare lo da aye ati orun (d) Olodumare lo bi wa
ORUKO OYE OBA ALAYE
- Kiini oruko oye Oba Ile-Ife (a) Ooni (b) Alaafin (d) Awujale
- Kiini oruko oye Oba ilu Oyo (a) Awujale (b) Alaafin (d) Soun
- Kiini oruko oye Oba Ilu Ijebu Ode (a) Soun (b) Ooni (d) Awujale
- Kiini oruko oye Oba Ilu Osogbo (a) Adiye (b) Ata Oja (d) Alake
- Kiini oruko oye Oba Ilu Egba (a) Alake (b) Awujale (d) Alaafin
Akanlo Ede
- Kiini itumo akanlo ede yii: Se aya gbangba
(a) Ki a ti aya siwaju (b) Ki a doju ko isoro pelu aiberu ati aifoya (d) Ki a ni aya lile
- Kiini itumo akanlo ede yii: Fi aake kori
(a) Ki eniyan ko jale lati se nnkan (b) ki afi aake si ori (d) Ki afi aake sa ori
- Kiini itumo akanlo ede yii: Kawo botan
(a) Ja-ole (b) ya-ole (d) Ya-ehona
- Kiini itumo akanlo ede yii: Fi iga gbaga (a) Ki eniyan kolu ara won,lati dan agbara won wo (b) ki eniyan jo lo si ibikan (d) Ki eniyan jo sun
- Kiini itumo akanlo ede yii: Edun arinle
(a) Edun ti o nrin ni ile (b) Edun ti o ti salo (d) Eni ti o ti lowo ri, sugbon tio pada raago
IWE KIKA: AJALA TA N NA O
- Kiini awon ara abule sefun Ajala (a) won buu (b) won na an (d) won kii
- Ajala maa nse ___________ kiri abule (a) ijangbon (b) agidi (d) omoluabi
- Omo ________________ ni Ajala (a) oponu (b) ole (d) lile
- Tan ni suur “tumo si __________________
(a) ni suuru (b) gba suuru tan (d) iluwa to le mu ni binu gan-an
- Itumo fa ijangbon ni __________ (a) da wahala sile (b)se wahala dopin (d) mu ijangbon dani