YORUBA LANGUAGE PRIMARY 2
FIRST TERM EXAMINATION
CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
- Orin akomo niwa: – Omo rere
- Omo rere kii ___________ (a) puro (b) sun
- Omo rere kii ___________ (a) jo (b) jale
- Omo rere kii ___________ (a) sole (b) kawe
- Omo rere kii ___________ (a) sise (b) seke
- Omo rere kii ___________ (a) seka (b) kawe
- Iwa omoluabi: – Itoju ati Oore Sise
- __________ nse baba Aina (a) Aisan (b) ebi
- __________ wa kii (a) Ajayi (b) Aina
- Iya __________ sa awon aso re si ita (a) Ade (b) Sola
- ________ nba ka awon aso naa (a) Kemi (b) Tola
- ___________ ati mama re nlo sode (a) ojo (b) ige
- Iroyin ati Asogba
- Ile-eko mi dara:- Tani o nsoro (a) Tunde (b) Alabi
- Bee ni, sugbon ko dara to ile eko ti wa:- Tani o fesi oro yii (a) Alaba (b) Tunde
- Woo bi ododo se po yi kii aasi ma ka:- Tani o tun soro (a) Tunde (b) Alaba
- Igi ti o lewa po ni ile-eko temi ju tire lo:- Tani o nso ro yii (a) Alaba (b) Tunde
- Wo maalu ti baba mi ra:- Tani o nsoro yii (a) Tunde (b) Alaba
- Aropo Imototo
- Fo _______ re bi o baji (a) eyin (b) apa
- Gba ______ re pelu (a) irun (b) ayika
- Ge ______ re lasiko toye (a) Ese (b) Irun
- ______ ti ngbe abe eekannaa ko kere (a) Alaafia (b) Arun
- Dakun dabo, jowo, wo ______ to mo (a) Aso (b) ago