A—Aaja. Yorùbá
Class: Pry one
Subject: Yoruba Studies
Akole:lilo leta ede yoruba loro
A—Aaja
B—Bata
D—Doje
E—Ejo
E—-Eye
F—-Fila
G—-Gele
Gb—-Gbaguda
H—-Hausa
I—-Igi
J—-Jagunjagun
K—Kiniun
L—–Labalaba
M—–Maalu
N—–Nahudu
O—-Ogongo
O—-Ogede
P—-Pepeye
R—-Rakunmi
S—-salubata
S—-sango
T—-Tafatafa
U—-Uku UK u
W—-Waala
Y—-Yanmuyanmu
Ise kilaasi
- A duro fun ___
(a) aja. (b)ologbo -
B duro fun kinni ____
(a) apo (b) bata -
D duro fun kinni _____
(a)doje (b)garuwa -
E duro fun kinni _____
(a) pepeye (b)ejo
5.E duro fun kinni____
(a) eye (b) igi