YORÙBÁ JSS 2 TÁÀMÙ KEJÌ
ÕSÊ | ORÍ ÕRÕ/ ÀKÓÓNÚ | ÀMÚŚE IŚË |
1. | LÍTÍRÈŚÕ: Àśàyàn ìwé (Ewì Àpilêkô) ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àwôn ewì tó wà nínú ìwé tí a yàn 2. Kókó õrõ b.a. ìwà ènìyàn; àwôn êdá mìíràn tí kì í śe ènìyàn, õrõ tó ń lô láwùjô,, ìkôlura êsìn, ipò obìnrin, ètò ôrõ-ajé, ìśakô/ ìśabo – gbogbolômô, éèdì. Àkíyèsí: Ó pôn dandan láti yan ìwé ewì tí ó ní àwôn àkóónú kókó õrõ wõnyí 3. Ônà èdè àti ìsôwölo-èdè. | OLÙKÖ 1. Ka ewì sí etígbõö àwôn akëkõö 2. Śe àlàyé lórí ewì tí a kà 3. Kô àwôn kókó õrõ jáde 4. Śe àlàyé ní kíkún lórí; * ônà èdè àti ìsôwölo-èdè. * kókó õrõ * Êkö tó köni * Darí ìjíròrò nípa àwôn kókó inú êkö yìí ni kíláásì AKËKÕÖ 1. ka ewì tí olùkö kà fúnra rç 2. kô àwôn kókó tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé 3. kópa nínú ìjíròrò tí olùkö śe nínú kíláásì. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé tí a yàn 2. Àwòrán àwôn ohun tí ewì dá lé lórí. |
2. | ÀŚÀ: Ogun àti Àlàáfíà ÀKÓÓNÚ IŚË 1. kí ni ogun? Kí sì ni ìdí tí ó fi máa ń wáyé? 2. Ogun Yorùbá láyé àtijö – orúkô ogun b.a. jálumi, kírìjí abbl – Àwôn jagunjagun b.a. Ìbíkúnlé, Ògúnmölá, Ògèdèýgbé abbl – Ohun èlò ogun b. a. ôfà, ôkõ, idà, ìbôn, oògùn. 3. Àýfààní ogun jíjà; õnà ìdáàbòbo ìlú çni, láti kó ìlú çni lërú, abbl 4. Àléébù ogun nípa ôsë tó ń śe – Dá õtá sílê – Run ìlú – Fa ìyàn, abbl 5. Õnà láti dëkun ogun jíjà. – Yíyàgò fún aáwõ. | OLÙKÖ 1. Śe àlàyé ohun tí ogun jë àti ìdí tí ó fi máa ń wáyé 2. Śe àlàyé nípa oríśiríśi ogun Yorùbá 3. Śe àlàyé àýfààní tí ó wà nínú ogun jíjà. (jë kí akëkõö mõ pé èyí mô níba. Àwôn ènìyàn péréte sì ni ó máa ń sábà kàn). 4. Śe àlàyé àléébù tí ó wà nínú ogun (jë kí akëkõö mõ pé èyí máa ń kan ènìyàn púpõ ju ti àýfààní rê lô). 5. Śe àlàyé pé kò sí ìfõkànbalê àti ìdàgbàsókè ní àkókò ogun. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö 2. śe àkôsílê sínú ìwé rç bí ó ti yç. 3. Wo àwòrán fíìmù, fídíò abbl tí olùkö fihàn 4. kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Téèpù 2. kásëêtì 3. Fídíò 4. fíìmù 5. Àwòrán 6. Tçlifísàn |
3. | ÈDÈ: Àtúnyêwò Ìsõrí Õrõ– Õrõ-Orúkô àti Õrõ-Ìśe ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àlàyé lórí õrõ-orúkô 2. Iśë tí õrõ-orúkô ń śe nínú gbólóhùn 3. Àlàyé lórí oríśiríśi õrõ-orúkô 4. Àlàyé lórí õrõ-ìśe 5. Iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn. | OLÙKÖ 1. Śe àlàyé lórí õrõ-orúkô 2. Śe àlàyé iśë tí õrõ-orúkô ń śe nínú gbólóhùn. B.a olùwà, àbõ àti êyán. 3. Dárúkô oríśiríśi õrõ-orúkô pêlú àpççrç wôn. B.a, orúkô ènìyàn, çranko, aśeékà, çlëmìí abbl. 4. Śe àlàyé lórí õrõ-ìśe 5. Śe àlàyé iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn. (jë kí akëkõö mõ pé òun ni òpómúléró àti kókó gbólóhùn) AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí ìsõrí õrõ-orúkô àti õrõ-ìśe. 2. Kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé. 3. Śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù 2. káàdì pélébé pélébé. |
4. | ÀŚÀ: Òýkà- Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún ÀKÓÓNÚ IŚË Òýkà láti Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún (251 – 300). Kíkà 260 = Õtàlénígba 280 = Õrìnlénígba 300 = Õödúnrún | OLÙKÖ 1. Tö akëkõö sönà láti ka òýkà láti Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún (251-300) 2. Śe àlàyé ìgbésê òýkà ní kíkún. AKËKÕÖ 1. ka òýkà láti Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún (251 – 300) 2. Dá òýkà tí a kô sójú pátákó mõ ní õkõõkan. 3. kô òýkà tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù tí a kô òýkà láti Õtàlénígba-ó-dín mësàn-án dé õödúnrún (251 – 300) sí. 2. káàdì pélébé pélébé tí a kô òýkà kõõkan sí. |
5. | ÈDÈ: Fónëtíìkì – Àpèjúwe ìró Köńsónáýtì ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Köńsónáýtì: b, d, f, g, gb, h, j, k, l, abbl 2. Àpèjúwe ìró köńsónáýtì – ibi ìsçnupè – õnà ìsçnupè Ipò tán-án-ná | OLÙKÖ 1. Kô köńsónáýtì Yorùbá lápapõ sójú pátákó fún akëkõö 2. Śe àpèjúwe ìró köńsónáýtì fún akëkõö lórí àtç köńsónáýtì – ibi ìsçnupè b.a. Àfèjì-ètèpè, Àfàfàsépè, àfèrìgìpè abbl – õnà ìsçnupè b.a. àréhön, àfúnnupè, àśenupè abbl – ipò tán-án-ná b.a akùnyùn tàbí àìkùnyùn AKËKÕÖ 1. fetí sí bí olùkö śe pe àwôn ìró köńsónáýtì náà 2. pe àwôn ìró köńsónáýtì náà bí olùkö śe pè wön. 3. Ya àtç ìró köńsónáýtì tí olùkö fi śe àpèjúwe ibi ìsçnupè, õnà ìsçnupè àti ipò tán-án-na 4. Śe àdàkô àwôn ohun tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù tí ó śe àfihàn àwòrán êyà ara ifõ 2. Káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn lëtà sí. |
6. | ÀŚÀ: Ogun àti Àlàáfíà ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Àýfààní ogun jíjà; õnà ìdáàbò bo ìlú çni, láti kó ni lërú abbl 2. Àléébù ogun nípa ôśë tí ó ń śe – Dá õtá sílê – Run ìlú – Fa ìyàn abbl 3. Õnà láti dëkun ogun jíjà – Yíyàgò fún aáwõ. | OLÙKÖ 1. Śe àlàyé àýfààní tí ó wà nínú ogun jíjà. (jë kí akëkõö mõ pé èyí mô níba. Àwôn ènìyàn péréte sì ni ó máa ń sábà kàn). 2. Śe àlàyé àléébù tí ó wà nínú ogun (jë kí akëkõö mõ pé èyí máa ń kan ènìyàn púpõ ju ti àýfààní rê lô). 3. Śe àlàyé pé kò sí ìfõkànbalê àti ìdàgbàsókè ní àkókò ogun. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àwôn àlàyé olùkö 2. śe àkôsílê sínú ìwé rç bí ó ti yç. 3. Wo àwòrán fíìmù, fídíò abbl tí olùkö fihàn 4. kópa nínú ìjíròrò tí olùkö darí OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Téèpù 2. kásëêtì 3. Fídíò 4. fíìmù 5. Àwòrán 6. Tçlifísàn |
7. | ÈDÈ: Òwe ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Oríkì òwe 2. Oríśiríśi òwe 3. ìlò òwe 4. Ìwúlò òwe | OLÙKÖ 1. Sô ìtumõ owe 2. jë kí akëkõö pa oríśiríśi òwe. B.a. ìbáwí, ìkìlõ, ìmõràn abbl 3. Kô ìbêrê àwôn òwe kan sójú pátákó ìkõwé fún àwôn akëkõö láti parí wôn 4. Śe àlàyé ìwúlò òwe fún akëkõö; b.a òwe ń jë kí èdè Yorùbá dùnún gbé kalê, ó wúlò fún láti sõrõ àśírí abbl. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö 2. Pa oríśiríśi òwe gëgë b olùkö śe darí 3. kô ìparí àwôn òwe tí olùkö kô sí ojú pátákó sí inú ìwé wôn. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Ìwé owe 2. pátákó ìkõwé |
8. | ÈDÈ: Àtúnyêwò ìsõrí õrõ-ìśe ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn * õrõ- ìśe çlëlà * õrõ-ìśe aláìlëlà * õrõ-ìśe agbàbõ * õrõ-ìśe aláìgbàbõ * õrõ-ìśe alápèpadà * õrõ-ìśe aśèbéèrè, abbl | OLÙKÖ 1. śe àlàyé iśë tí õrõ-ìśe ń śe nínú gbólóhùn fún àwôn akëkõö b.a. òun ni kókó inú gbolohun. 2. Śe àkôsílê oríśiríśi õrõ-iśë pêlú àpççrç fún õkõõkan wôn. Bí àpççrç; Õrõ-ìśe alápèpadà – Ç rò mi ro ire AKËKÕÖ 1. Tëtí sí àlàyé olùkö lórí iśë tí õrõ-ìśe ń śe àti àwôn oríśiríśi õrõ-ìśe tí ó wà. 2. kô àwôn àpççrç tí olùkö śe sínú ìwé 3. śe àwôn àpççrç tìrç lábë ìdarí olùkö. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Kádíböõdù 2. Káàdì pélébé pélébé |
9. | ÈDÈ: Fónëtíìkì – Àpèjúwe Ìró Fáwëlì ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Fáwëlì: * Àránmúpè – an, çn, in, un, ôn * Àìránmúpè – a, e, ç, i, o , ô, u 2. Àpèjúwe ìró fáwëlì * ipò ahön * ipò ètè * ipò àfàsé | OLÙKÖ 1. kô fáwëlì Yorùbá lápapõ sójú pátákó fún akëkõö 2. śe àpèjúwe ìró fáwëlì fún àwôn akëkõö lórí àtç ìró fáwëlì. Bí àpççrç: – ipò ahön: iwájú ahön, àárin ahön àti êyìn ahön – ipò ètè: pçrçsç tàbí roboto – ipò àfàsé: Àránmúpè àti Àìránmúpè AKËKÕÖ 1. Fetí sí bí olùkö śe pe àwôn ìró fáwëlì náà. 2. pe àwôn ìró fáwëlì náà bí olùkö śe pè wön. 3. Ya àtç ìró fáwëlì tí olùkö fi śe àpèjúwe ìró fáwëlì àìránmúpè àti àránmúpè 4. śe àdàkô àwôn ohun tí olùkö kô sójú pátákó sínú ìwé. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. kádíböõdù tí ó śe àfihàn àtç ìró fáwëlì àránmúpè àti àìránmúpè 2. káàdì pélébé pélébé tí a kô àwôn lëtà sí. |
10. | ÀŚÀ: Ìpolówó Ôjà ÀKÓÓNÚ IŚË 1. Ìdí tí a fi ń polówó ôjà 2. Bí a śe ń polówó ôjà: b. a. êkô tútù, ç ç jçran êkô. 3. Ôgbön ìpolówó ôjà ní ayé àtijö àti òde òní. B.a. ìpolówó ôjà lórí rédíò, tçlifísàn, ìwé ìròyìn, ìpàtç, ìkiri abbl.
| OLÙKÖ 1. Tç ìpolówó ôjà tí a ti tê sórí téèpù fún àwôn akëkõö gbö. 2. fún àwôn akëkõö ní àýfààní láti śe ìpolówó ôjà ní kíláásì. 3. kó akëkõö lô śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ. AKËKÕÖ 1. Tëtí sí téèpù tí olùkö tê 2. kópa nínú śíśe ìpolówó ôjà nínú kíláásì. 3. śe àbêwò sí ôjà tàbí ìdíkõ láti gbö oríśiríśi ìpolówó ôjà. OHUN-ÈLÒ ÌKÖNI 1. Àtç 2. Fídíò 3. Rédíò 4. Êrô agbõrõ sílê 5. Téèpù 6. Ìpolówó ôjà lóríśiríśi nínú ìwé ìròyìn abbl. |
11. | ÀTÚNYÊWÒ ÊKÖ | |
12. | ÌDÁNWÒ |