Yoruba Primary 4 Examination Second Term
NAME:…………………………………………………………………………………… ORIKI ILU
- Ilu wo ni a nki bayii pe, mesi ogo, nile oluyole, nibi ole gbe njare onihun (a) Ibadan (b) Akura (d) Oyo
- Ilu wo ni a nki bayi pe, akete ile ogbon, aromisa legbe legbe (a) Egba (b) Eko (d) Akure
- ) Ilu wo ni a nki bayi pe: oloyemekun, omo a muda sile mogun enu pani (a) Akure (b) Ilorin (d) Ondo
- .) Ilu wo ni a nki bayi pe; omo ajifi kalamu damo leko arise kandun kandun, ilu to jinna to sunmo alujona (a) Egba (b) Oyo (d) Ilorin
- Ilu wo ni a nki bayii pe, omo lisabi, oniruuru – po nile Alake (a) Ogbomoso (b) Egba (d) Ijesa
ONKA NI EDE YORUBA
Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba:
- 75 (a) arundinlogbon (b) arundinlogoji (d) arundinlogorun
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 45 (a) arundinladota (b) arundinlogun (d) arundinlogorun
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 90 (a) ogorun (b) adorun (d) ogota
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 110 (a) ogorin (b) ogorun (d) adofa
- Kini oruko awon nomba yii ni ede Yoruba: 65 (a) arundinladorin (b) arundinlogoji (d) arundinnigba
ASO ILE YORUBA
- Ewo ni aso ile wa ninu awon oruko wonyii (a) alari (b) akara (d) seti
- Ara ti obinrin fi aso ran ni _____ ati _____ (a) gele ati ipele (b) iro ati buba (d) oyala ati dansiki
- Ara to okunrin nfi aso ran ni ______ ati _____ (a) buba ati sokoto (b) iro ati gele (d) tobi ati oyala
- Aso ati a nran ti o ngun de orun ese ni ______ o dabi jalamia ti won ba ran tan (a) agbada (b) dandogo (d) gbariye
- Aso ti o jo agbada, sugbon ko tobi to agbada ti a ba ran tan ni a npe ni _____ (a) dansiki (b) gbariye (d) oya
AGBON TA GBONJU
- Kini o ta gbonju? (a) ikamudu (b) oyin (d) agbon (e) kan-in-kan-in
- Ninu eko yii, baba gbonju ko fe ki awon omo oun ya______ (a) ole (b) ole (d) olojukokoro (e) alaigboran
- Itumo se imele ni ______ (a) roju (b) gun ope (d) ja ole (e) ya ole
- __________ ni baba gbonju (a) olowo (b) akikanju (d) ole (e) okuroro
- Kini koje ki baba gbonju lo si oko (a) idiwo kekere (b) ise nla (d) oro aje (e)