Àwọn ohun tí ó wà ní inú Kíláàsì Yoruba Primary 1 Second Term Lesson Notes


DEETI: ỌJỌ́BỌ̀ ỌJỌ́ KỌKÀNLÁ OṢÙ SẸẸRẸ, 2024. KÍLÁÀSÌ: alákọ̀bẹ́rẹ̀ olódún kíní IṢẸ́: YORÙBÁ ỌJỌ́ ORÍ AKẸ́Ẹ̀KỌ́: ỌDÚN MẸ́FÀ SÍ MÉJE ORÍ Ọ̀RỌ̀: Àwọn ohun tí ó wà ní inú Kíláàsì ÌWÉ ÌTỌ́KASÍ: Ayọ̀ Adésànyà et’al(2018) Ìwé Kíkà Àsìkò Tuntun, Ojú ewé Kejì. OHUN ÈLÒ ÌKỌ́NI: Sáàtì tí ó ṣe àfihàn àẁorán nǹkan lórísìírísìí. ÌMỌ̀