SECOND TERM EXAMINATION
CLASS: PRIMARY 2
SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
ERE AYO
- ________ ni igi gbooro gidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo (b) awo ayo
- Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) mejo (b) merin
- Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun (b) osi
- Enikan _________ ni o nta ayo olopon leekan naa (a) merin (b) meji
- Omo ayo ______ ni o ngbe ni oju opon ayo lapapo (a) mejidinladota (b) merinlelogun
ALO APAMO
- Alo o, alo o, okun nho yaya, osa nho yaya, omo buruku tori bo, kini o (a) irin (b) omorogun
- Alo o, alo o, opa tinrin kanle, o karun, kini o (a) ojo (b) agbara
- Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruko bi igba omo, gbogbo won lo le tiro, kini o (a) ata (b) ewa
- Alo o, alo o, mo nlo soyo; mo koju soyo, mo nbo loyo, mo koju soyo, kini o (a) ilu (b) igba
- Alo o, alo o, aso baba mi kan laelae, aso baba mi kan laelae, eti lo ngbo, kii gbo laarin, kini o (a) agbara (b) odo
ALO APAGBE: IJAPA ATI OKERE
- _________ ati okere je ore (a) asin (b) ijapa
- _______ kii se ore won (a) ijapa (b) asin
- Ijapa la ija ___________ (a) ogbon (b) eru
- Ija sele laarin ________ ati ______ (a) ijapa ati asin (b) asin ati okere
- Inu bii asin gidigidi, o sig e e je ni __________ (a) imu (b) ese
IMOTOTO ILE
- _______ nge koriko ti o wa ni ayika ile (a) Tunde (b) Kola
- ________ ngba idoti ati panti inu ile sita (a) Yemi (b) Bola
- Mama ________ sese fo aso tan ni (a) Bola (b) Kemi
- Baba ________ naa fe sun panti ti won ti ko jo nina (a) Kola (b) Tunde
- O n sa wonsi ori _________ isasosi (a) okun (b) igi
About The Author
Edu Delight Tutors
Am a dedicated educator with a passion for learning and a keen interest in technology. I believe that technology can revolutionize education and am committed to creating an online hub of knowledge, inspiration, and growth for both educators and students. Welcome to Edu Delight Tutors, where learning knows no boundaries.