3RD TERM EXAM QUESTIONS PRIMARY 1 YORUBA

 

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION 

CLASS: PRIMARY 1

SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

NAME:……………………………………………………………

Alo Apamo: 

  • Alo o, alo o, ki lo bo somi, ti ko ro to, kiini o (a) okinni (b) irin
  • Alo o, alo o, opa tinrin kanle o kanrun, kiini o   (a) igi   (b) ojo
  • kilo ba oba jeun, ti ko palemo     (a) Esinsin      (b) Ijalo
  • Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruku bi igba omo gbogbo won lo le tiro, kini o  (a) Ata      (b) Ewa 
  • Alo o, alo o, mo nlo soyo, mo koju soyo, mo nbo loyo, mo koju soyo, Kiini o 

(a) Ilu (b) Agba

DI AWON ALAFO WONYII PELU LETA TI O YE:

A ________   D _______  E _______  G  _________  I  _______ J _________ L

______ N _______ O _______ R __________

ITAN KOKO IYA ARUGBO 

  • __________ kan wa ni aye atijo (a) Baba (b) Iya
  • O bi omo ________ (a) mewa (b) meje 
  • _________ ninu won loji koko iya Arugbo ile won je (a) okan (b) meta
  • Ssugbon ______ ko gba won gbo (a) baba Arugbo  (b) iya Arugbo
  • Nigba ti omo _____ gun ori  afara ni afara ja (a) kefa (b) keji

 

Imototo 

  • Fo ___________ re bi o baji (a) eyin (b) inu 
  • Gba _________ re pelu (a) iwaju (b) ayika  
  • Ge _____________ re ti ogun sobolo (a) eekanna (b) ese 
  • _______ ti nbge abe eekanna ko kere  (a) arun   (b) aisan
  • Ge _________ re lasiko ti o ye (a) owo (b) irun  

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share