YORUBA LANGUAGE PRIMARY 2 FIRST TERM EXAMINATION
FIRST TERM EXAMINATION 2021/2022
CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………
ORIN AKOMONIWA: OMO RERE
i.) Omo rere kii ___________ (a) puro (b) sise
ii.) Omo rere kii ___________ (a) kawe (b) jale
iii.) Omo rere kii ___________ (a) we (b) seke
iv.) Omo rere kii ___________ (a) ja (b) sun
v.) Omo rere kii ___________ (a) rerin (b) sole
IWA OMOLUABI: ITOJU ATI OORE SISE
1.) _______________ nse baba Aina (a) Aisan (b) Aarun
2.) _________________ wa kii. (a) Ige (b) Aina
3.) ________________ fee ro (a) omi (b) ojo
4.) Iya ________________ sa awon aso re si ita (a) Ade (b) Kola
5.) Ojo ri okunrin _______ kan lona (a) abuke (b) aro
IROYIN ATI ASOGBA
1.) Ile-eko mi dara, talo nsoro yii? (a) Tunde (b) Alaba
2.) Bee ni, sugbon ko dara to ile-eko tiwa? talo lo nsoro yii? (a) Alaba (b) Tunde
3.) Wo o bi ododo se po yi kilaasi mi ka, talo nsoro yii? (a) Alaba (b) Tunde
4.) Igi ti ole wa po ni ile-eko temi ju tire lo, talo nsoro yii? (a) Tunde (b) Alaba
5.) _________________ ati ___________________ ni won jo nsoro
AROFO IMOTOTO
1.) Fo ______________ re bi o baji (a) eyin (b) irun
2.) Gba __________________ re pelu (a) eru (b) ayika
3.) Ge _______________ re lasiko to ye (a) irun (b) imu
4.) Ge _______________ re to gun sobolo (a) ese (b) eekanna
5.) Fi _________________ we kara das aka (a) ose (b) ewe
YORÙBÁ PRIMARY 3 FIRST TERM EXAMINATION
YORUBA LANGUAGE PRIMARY 4 FIRST TERM EXAMINATION
.