Akole: onka ni ede Yoruba lati ori aarun de ori ogowa(5 – 200)

 

Class: Pry six

Subject: Yoruba Studies

 

Akole: onka ni ede Yoruba lati ori aarun de ori ogowa(5 – 200)

 

5-Aarun

10-Eewa

15-Aarundinlogun

21-16-Erindinlogun

17-Etadinlogun

18-Ejidinlogun

19-okandinlogun

20-Ogun

21-Okanlelogun

22-Ejilelogun

23-Etalelogun

24-Erinlelogun

25-Arundinlogbon

26-Erindinlogbon

27-Etadinlogbon

28-Ejidinlogbon

29-Okandinlogbon

30-Ogbon

35-Aarundinlogoji

40-Ogoji

45-Arundinladota

50-Adorable

55-Arundinlogota

60-Ogota

65-Arundinladorin

70-Adorin

75-Arundinlogorin

80-Ogorin

85-Aarundinladorin

90-Adorun

95-Arundinlogorun

100-Ogorun

105-Arundinladofa

110-Adofa

115-Arundinlogofa

120-Ogofa

125-Arundinladoje

130-Adoje

135-Arundinlogoje

140-Ogoje

145-Arundinladojo

150-Adojo

155-Arundinlogojo

160-Ogojo

165-Arundinladosan

170-Adosan

175-Arundinlogosan

180-Ogosan

185-Arundinladowaa

190-Adowa

195-Arundinlogowa

200-Ogowaa.

 

Ise kilaasi:

 

  1. Kinni oruko nomba yii ni ede Yoruba 95?

(a) Arundinlogorun

(b) Arundinlogbon

 

  1. Kinni oruko nomba yii ni ede yoruba 110?

(a) Ogoje

(b) Adofa

 

  1. Kinni oruko nomba yi ni ede yoruba 130?

(a) Adoje

(b) Ogojo

 

  1. Kinni oruko nomba yi ni ede yoruba 160?

(a) Ogojo

(b) Ogosan

 

  1. Kinni oruko awon nomba yii ni ede yoruba 100?

(a) Adowaa

(b) Ogorun

 

  1. Kinni oruko nombaa yii ni ede yoruba 200?

(a) Ogowaa

(b) Ogorin

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *