YORÙBÁ basic three
YORÙBÁ basic three
- Ninu alifabeeti lati ri faweli ati _____ (a) Faweli (b) Konsonanti (d) Maarun-un
- Faweli aranmupe je _____ (a) merin (b) meje (d) marun-un
- Faweli aranmupe je _____(a)marun-un (b) mejila (d) merin.
- Oro idakeji fun baba ni _____ (a) Iya (b) Ore (d) Ota
- Oro idakeji fun oko ni _____ (a) egbon (b) aburo (d) iyawo
- “10” ni ede Yoruba ni _____ (a) Eewaa (b) Merinla (d) mejo.
- “15” ni ede Yoruba ni _____ (a) metala (b) meedogun (d) merinla
- “18” ni ede Yoruba ni _____ (a) mejidinlogun (b) metala (d) merindinlogbon
- Ogun ni ede Geesi ni (a) 15 (b) 20 (d) 30
- Ogbon ni ede Geesi ni _____ (a) 30 (b)20 (d) 40.