Yoruba basic four Faweeli

Yoruba basic four

  1. Faweli meloo lo wa ninu oro yii ? Aso (a) Eyookan (b) meji (d) meta
  2. Faweli meloo lo wa ninu oro yii ? Bata (a) meji (b) meta (d) merin
  3. Konsonanti inu oro yii ni IJAPA (a) I,J (b) J,P (d) P,A
  4. Konsonanti inu oro yii ni IGO (a) I (b) G (d)O
  5. Ojo _____ lo wa ninu ose kan (a) marun-un (b) meje (d) mefa[mediator_tech]

Bawoo ni awon Yoruba se n pea won ojo wony

  1. Sunday ni Yoruba n pe ni _________________________
  2. Monday ni Yoruba n pe ni ________________________
  3. Tuesday ni Yoruba n pe ni _________________________
  4. Wednesday ni Yoruba n pe ni ______________________
  5. Thursday ni Yoruba n pe ni ________________________.

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share