Yoruba Second Term Examination Primary 3
NAME:…………………………………………………………………………………… OTITO BORI
- Ilu wo ni itan yii ti sele _____ (a) Ayokooto (b) Ayedande
- Kii ni ise Mosun (a) agbejoro (b) onisowo
- Talo se ijanba fun Mosun? (a) Agbalagba kan (b) Omodekunrin kan
- Bawo ni won se ko ba Mosun? (a) won ba Mosun ja (b) won fi oja fayawo ranse si iso re
- Bawo ni Mosun se bo ninu isoro re? (a) awon olopaa fi sile (b) omode kunrin kan lo tu asiri
ALO APAMO
- Alo o, alo o, opo baba alo kan laelae, opo baba alo kan laelae, ojo to ba de fila pupa ni iku de ba a o, kini o (a) abela (b) omorogun
- Alo o, alo o, ikoko rugudu feyin tigbo, kini o (a) ijapa (b) igbin
- Alo o, alo o, kini koja niwaju oba ti ko ki oba, kini o (a) agbara (b) sigidi
- Alo o, alo o, awe obi kana je doyo, kini o (a) enu (b) ahon
- Alo o, alo o, yara kotopo, kiki egun, ki ni o (a) enu (b) ibepe
ALO APAGBE: IJAPA ATI ERIN
- Kini awon oba fi maa nbo ori won laye atijo (a) eranko nla (b) eranko wewe
- Bawo ni ijapa se je si erin (a) ota (b) ore
- Ona wo ni ijapa gba mu erin wo ilu (a) o fun ni akara (b) o fun ni robo aladun
- Ileri wo ni kabiyesi se fun ijapa (a) o da ohun ini resi meji (b) o je ijapa ni iya
- Eko wo ni itan yii ko wa? (a) okowa ki a maa sora ni ile aye (b) o kowa ki a maa sora fun awon odale ore
SISE KANGO
- Iya __________ fe din kango (a) Ayoka (b) Adunni
- ________ ya agbado wa lati oko (a) Egbon (b) Baba
- Iya Adunni re agbado naa sinu ______ nla kan (a) ikoko (b) agba
- O bu epo pupa sinu _______ (a) ina (b) agbada
- Nigba ti __________ gbona daadaa (a) epo (b) omi