Tag: JSS 3

ASA IRANRA – ENI LOWO (COMMUNAL ASSISTANCE)

ASA IRANRA – ENI LOWO (COMMUNAL ASSISTANCE) Asa iranra – eni lowo je ona ti awon Yoruba fi maa n ran ara won lowo ni aye atijo. Asa yii maa n saba jeyo ninu ise oko riro, ile kiko, owo yiya tabi n kan miiran. Asa iranra – eni lowo maa n mu ki ise

ERE IDARAYA

OSE KEFA AKORI EKO: ERE IDARAYA Ere idaraya ni awon ere t tewe – tagba maa n se lati mu ki ara won jipepe. Bi awon Yoruba se feran ise – sise to bee naa ni won ni akoko fun ere idaraya. Akoko ti ise ba dile tabi awon eniyan ba dari bo lati ibi

ATUNYEWO AWON EYA GBOLOHUN

OSE KẸFÀ  AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA GBOLOHUN Gbolohun ni oro tabi akojopo oro ti o ni itumo. Gbolohun le je ipede ti o ni itumo tabi ni ise ti o n se nibikibi ti o ba ti jeyo. Bakan naa a le pe gbolohun ni oro ti a le pin si spola oro-oruko ati

EWI AKOMOLEDE

OSE KÀRÚN  AKORI EKO: EWI AKOMOLEDE JE OLOGBON OMO     A ko mi nifee     Mo mo fee su     A ko mi lror     Mo moro atata I pe     Awon agba lo ko mi ni samusamu     Ti mot i menu ije     Ife mi yato si teni ti n yinmu     Oro

APOLA INU EDE YORUBA

OSE KẸRIN  AKORI EKO: APOLA INU EDE YORUBA Apola je okan ninu awon abala ihun gbolohun ede Yoruba. Gbolohun le je eyo oro kan tabi akojopo oro ti oni itumo. Ihun gbolohun ede Yoruba dabi igba ti a bah un eni, a ni lati to awon oro wonyii jo lona ti yoo fi le e

FONOLOJI EDE YORUBA

    OSE KINNI AKORI EKO: FONOLOJI EDE YORUBA Fonoloji ni imo eto amulo iro lapapo. Eko ti o je mo bi a se n to iro papo ninu oro ede Yoruba ti oro ede Yoruba si fi yori si gbolohun ede Yoruba ni a n pen i fonoloji. Iro Faweli: Eyi ni awon iro

Itoju Alaboyun (1)Igbagbo Yoruba nipa agan, omo bibi ati abiku.

Ò̩SÈ̩ 3 EDE: Akoto siwaju JEC 1974; Agbeyewo ipinnu 1974 ti ijoba apapo lori akoto Yoruba (Joint Consultative                     Committee-JCC ASA: Itoju Alaboyun (1)Igbagbo Yoruba nipa agan, omo bibi ati abiku. Awon ti oyun nini wa fun (tokotaya). Ona ti a le gba din bibi abiku ku lawujo wa; Orisiirisii jenotaipu eje to wa ati

ÒǸKÀ LÁTI E̩GBE̩RÚN ME̩WAA TITI DE E̩GBÀÁWÀÁ (10,000-20,000)

Ò̩SÈ̩ KIINI AKOONU ISE 1    EDÉ, ÀSA ATI LITIRESO:s Agbeyewo idanwo taamu to koja; idahun si awon ibeere.   2.    ÈDÈ: Òǹkà láti e̩gbe̩rún me̩waa titi de e̩gbàáwàá (10,000-20,000). LITIRESO: Kika iwe litireso ti a yan fun taamu yii:- Agbeyewo oro akoso Onkowe, ohun ti itan naa da lori.   ÀKÓÓNU IS̩É̩ ÒǸKÀ LÁTI E̩GBE̩RÚN

PHE JSS 3 First Term Physical and Health Education Lesson Plan with Notes

PHYSICAL AND HEALTH EDUCATION FIRST TERM WEEKLY LESSON NOTES  PHYSICAL FITNESS PRE-COLONIAL OR FOLK DANCES Types of Computer Games FIELD EVENTS – POLE VAULT BALL GAMES HOCKEY DEFINITION PENTATHLON AND DECATHLON CAREER GUIDANCE IN PHYSICAL EDUCATION CONTACT GAMES – TAEKWONDO JSS 3 FIRST TERM EXAMINATION PHE PHYSICAL AND HEALTH EDUCATION

JSS 3 FIRST TERM EXAMINATION PHE PHYSICAL AND HEALTH EDUCATION

CLASS:                  JSS 3 SUBJECT:                             P.H.E   Gymnastics originated in ______(a) Rome (b) Spain (c) Greece (d) France Taekwondo is a ______National sport (a) Korean (b) Chinese (c) Japanese (d) Taiwan A skeleton contain a softer `tissue called ______(a) Bondage (b) Cartilage (c) Outage (d) Tillage A______is a point where two or more bones meet. (a)