ALPHA TERM ILAANA ISE NI SAA KINNI FUN SS3 YORUBA LANGUAGE OSE AKORI EKO 1 EDE – Itesiwaju eko lori oro ise; Alaye lori orisii ati ilo re ninu gbolohun ASA – Afiwe asa Isinku abinibi ati eto sinku ode oni. Ayipada to ti de ba Asa isinku abinibi tabi atohunrinwa LITIRESO – Agbeyewo iwe
Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 10 OSE KEWAA ORO-ORUKO – oriki – orisiirisii oro oruko. – ise ti oro oruko n se ninu gbolohun. – lilo oro oruko ninu gbolohun. AKOONU : – Oro –oruko ni awon oro ti won le da duro nipo oluwa, abo tabi
Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 9 OSE KESAN-AN AKAYE Akoonu Eka pataki ni akaye je ninu ede Yoruba. Akaye gba suuru lati ka, o gba iyosira ati amodaju awon koko-oro ti ibeere ba da le lori. Ayoka oloro wuuru Ayoka le je ewi Ayoka le je asotan
Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 8 OSE KEJO AAYAN OGBUFO Aayan ogbufo ni ise titumo ede kan si ede miiran. Ki ogbufo to le kogo ja ninu itumo ede, o gbodo mo tifun tedo ede Geesi , ki o si le tusu ede Yoruba naa de isale ikoko. Kii
Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 7 OSE KEJE IYATO TI O WA LAARIN ORO-APONLE ATI APOLA-APONLE Isori oro ni oro-aponle sugbon apola aponle gbooro ju oro-aponle lo. Apeere: Ojo tete de O de nigba ti Ojo wole Isori oro-aponle nikan ni oro-aponle je mo sugbon apola aponle je
Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 6 OSE KEFA AROKO ONIROYIN Akoonu: Aroko Oniroyin:- je mo iroyin sise tabi itan isele ti o ti koja seyin ti o si se oju eni ti a n royin re ni sise-n-tele ninu aroko oniroyin fun elomiran ti ko si nibe. A rii
Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 5 OSE KARUN – UN ORO – AGBASO Akoonu Oro agbaso naa ni a mo si afo agbaran. Oro agbaso:- je siso oro ti a gbo lenu oloro fun elomiran. Iru oro tabi iroyin bee gbodo je eyi to ti koja. Oro agbaso le
Subject : Yoruba Class: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: WEEK 4 OSE KERIN IBA-ISELE – Oriki – Orisii iba-isele – Awon wunren ti o toka iba-isele Akonu: ORI-ORO: ASIKO ATI IBA ISELE ORIKI EYA IBA ISELE AKOONU Asiko je oro girama ti a maa n lo lati fi toka si asiko ti isele kan
SUBJECT: YORUBA CLASS: SS 3 TERM: FIRST TERM OSE KETA DIDA ORO ORUKO TI A SEDA MO YATO SI EYI TI A KO SEDA Ori-oro-: Dida oro – oruko ti a seda mo ninu gbolohun Isunki ati aranmo ninu awon oro–oruko ti a seda Akoonu Bi a se le da oro – oruko ti a
SUBJECT: YORUBA CLASS: SS 3 TERM: FIRST TERM WEEK: SECOND WEEK OSE KEJI ISORI GBOLOHUN Oríkì Ìsorí gbólóhùn pèlú àpẹẹrẹ Akóónú Gbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé. Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún. A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí
SUBJECT: YORUBA CLASS: SS 3 TERM: FIRST TERM ORO – ISE OSE KIN-IN-NI ORO – ISE Oro – ise ni oro tabi akojopo oro ti o n toka si isele tabi nnkan ti Oluwa se ninu gbolohun. Oro–ise je opomulero fun gbolohun laisi oro–ise ninu gbolohun ko le ni itumo. Apeere
ILANA ISE SAA KIN-IN-NI ISE: EDE YORUBA KILAASI: S. S.3 Ose Kinni – Ede – Isori – Oro Oro – Ise Oriki – Orisii Ati ilo re. asa – Afiwe, asa isinku abinibi, omo leyin Kiristi ati musulumi Litireso: Ogbon itopinpin