SS 2 FIRST TERM LESSON NOTE YORUBA
ILAANA ISE NI SAA KINNI FUN SS2 YORUBA LANGUAGE OSE AKORI EKO 1 EDE – Atunyewo lori Aroko ajemo isipaya: Ilana ero aroko ajemo isipaya Akole, Ifaara, koko oro, agbalo gbdo Alaye kikun lori eto ipin afo Kiko aroko lori akole bii Omi, Iyan,Oja ati bee lo ASA – Atunyewo lori eko ile: Ibowofagba, ikini,