Category: YORUBA PRIMARY 4

3RD TERM EXAM QUESTIONS PRIMARY 4 YORUBA LANGUAGE

  . THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… AYEWO Iru leta wo ni a nko si obi? (a)  leta gbefe       (b) leta aigbefe (d) leta onibeji Ise Agbe dara ju ise dokita lo  je apeere aroko ________ (a) oniroyin       (b) alalaye       

Third Term Examinations Primary 4 Yoruba

THIRD TERM SUBJECT: YORUBA                                          CLASS: KILAASI  KERIN Dahun  gbogbo  awon  ibeere  wonyi Oriki  orile  yato  si  oriki  ilu (a)  beeko  (b)  beeni  (d)  n ko  mo Kini ogota  ni nomba  (a)  50  (b)  70  

Yoruba Primary 4 First Term Examinations

FIRST TERM EXAMINATION 2021/2022 CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………… IWE KIKA: ASIMU OLE 1.) __________ ni oruko oja ilu pokii (a) ikilo (b) oroorun (d) ayelu 2.) Ohun ti o se akoba fun pokii ni pe _____________ (a) o ni ore pupo (b) o nra epa je (d) o nlo si oja ayelu

SECOND TERM EXAM BASIC 4 YORUBA

Edu Delight Tutors LAGOS SECOND TERM EXAM BASIC 4 1. Ewo ni ki se elo idana ni ile yoruba (a) Epo pupo (b) isu (c) ewa 2. Oko ati iyawo maa n wo aso __________ ninu igbeyawo (a) Igbalode (b) ibile (c) idoti 3. Ewo ni kii nse orisi owe ni ile Yoruba? (a) Owe

Awon omo àti orúkọ amutorunwa

Pry four Akole:Awon omo amutorunwa   Awon omo wo ni ape ni omo amutorunwa?Omo amutorunwa ni awon omo ti a bi ni ipase ami iyanu ona ti won gba waye yato si bi a ti bi omo orisirisi ona ni won gba waye. Awon omo amutorunwa naa ni awon wonyii 1.Ige–ige ni omo ti abi

Àwọn Ọjọ́ Tí Ó Wà Ninu Ọṣẹ̀

Pry four Akole:ojo ti owa ninu ose ati osu ti owa ninu odun.   OJO TI OWA NINU OSE   Sunday-ojo Aiku Monday-ojo aje Tuesday-ojo isegun Wednesday–ojo ru Thursday-ojo bo Friday–ojo eti Saturday –ojo abameta OSU TI OWA NINU ODUN January–seere February–erele March——erena April———igbe May———-ebibi June———-okudu July————-agemo August———Ogun September—-owewe October———–owara November——–belu December———ope Ise kilaasi 1.

onka ni ede Yoruba lati ori aarun de ori ogorun(5-100

Pry four Ose kinni Akole:onka ni ede Yoruba lati ori aarun de ori ogorun(5-100) 5-Aaron 10-Eewa 15-Aarundinlogun 21-16-Erindinlogun 17-Etadinlogun 18-Ejidinlogun 19-okandinlogun 20-Ogun 21-Okanlelogun 22-Ejilelogun 23-Etalelogun 24-Erinlelogun 25-Arundinlogbon 26-Erindinlogbon 27-Etadinlogbon 28-Ejidinlogbon 29-Okandinlogbon 30-Ogbon 31-okanlelogbon 32-ejilelogbon 33-etalelogbon 34-erinlelogbon 35-Aarundinlogoji 36-erindinlogoji 37-etadinlogoji 38-ejidinlogoji 39-okandinlogoji 40-Ogoji   Ise kilaasi Kinni oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba   1.32

Alo apamọ́ àti àwọn ìdáhùn wọn

  Class: Pry four Subject: Yoruba Studies Akole: Alo apamo Alo o aalo, ikoko rugudu feyin ti gbó Kinni: IGBIN Alo o aalo, ile gbajumo kik imi eran Kinni: IBEPE Alo o aalo, iyara kotopo kiki ègún Kinni:ENU Alo o aalo, opo baba alo kan lailai opo baba alo lailai ojo to ba de fila

OWE ILE YORUBA (Pry 4 )

Class: Pry four Subject: Yoruba Studies Akole:OWE ILE YORUBA 1.Operekete ndagba,inu adamo nbaje adi baba tan inu bi won Gele o dun bi ka mo we, kamowe ko dabi koyeni,koyeni kodabi kamolo Omo ti yoo je asamu,kekere lo ti nsenu samusamu 4, Aja ti yoo sonu,kin gbo feere olode 5.Eni ti yoo je oyin inu

Akole Eko Tóòni : Onka ni ede Yoruba lati ori Aarun de ori Ogorun (5-100):

Date: Friday, 1st May, 2020. Class: Pry four Subject: Yoruba Studies   Akole: Onka ni ede Yoruba lati ori Aarun de ori Ogorun (5-100):   5-Aaron 10-Eewa 15-Aarundinlogun 21-16-Erindinlogun 17-Etadinlogun 18-Ejidinlogun 19-okandinlogun 20-Ogun 21-Okanlelogun 22-Ejilelogun 23-Etalelogun 24-Erinlelogun 25-Arundinlogbon 26-Erindinlogbon 27-Etadinlogbon 28-Ejidinlogbon 29-Okandinlogbon 30-Ogbon 35-Aarundinlogoji 40-Ogoji 45-Arundinladota 50-Adorable 55-Arundinlogota 60-Ogota 65-Arundinladorin 70-Adorin 75-Arundinlogorin 80-Ogorin 85-Aarundinladorin 90-Adorun
Use the search box to search for any topics or subjects that you want