YORUBA PRIMARY 3

Revision Yoruba Primary 3 First Term Lesson Notes Week 11

Subject: Yoruba Class: Primary 3 Term: First Term Week: 11 Topic: Revision Sub-topic: Yoruba Language Duration: 40 minutes Entry Behaviour: Students should be familiar with basic Yoruba words and expressions. Key words: Yoruba, language, revision, words, expressions. Behavioral Objectives: Students will recall and pronounce basic Yoruba words. Students will use common expressions in everyday conversations.

Yoruba Primary 3 First Term Lesson Notes

FIRST TERM EXAMINATION 2017/2018 CLASS: PRIMARY 1 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:… DI AWON ALAFO WONYII PELU LETA TI OYE A ________ O ________ Ę ________ G _________ I _________ J ________ L ________ N _________ Ǫ ________ R ________ Ș ________ U _________ Y DI AWON ALAFO WONYII Melo ni iro faweli airanmupe ede Yoruba

3RD TERM EXAM QUESTIONS PRIMARY 3 YORUBA LANGUAGE

THIRD TERM PROMOTIONAL EXAMINATION  CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… ASA IKINI  Nibo ni Alake  ba iya re lo?   (a) si odo iyasola (b) si odo iya tunde Kiini iya sola sese se? (a) osese lo si ile  iwosan (b) osese bimo   Bawo ni a sen ki eni ti o ba sese bimo? 

Third Term Examinations Primary 3 Yoruba

THIRD TERM SUBJECT: YORUBA                                          CLASS: KILAASI  KETA Dahun  gbogbo  awon  ibeere  wonyi Apa  ibo ni a ti gbodo maa  rin ti a ba n rin ni opopona oko (a) apa osi  (b)  apa otun  (d) 

Third Term Examinations Primary 3 Yoruba

THIRD TERM SUBJECT: YORUBA                                          CLASS: KILAASI  KETA Dahun  gbogbo  awon  ibeere  wonyi Apa  ibo ni a ti gbodo maa  rin ti a ba n rin ni opopona oko (a) apa osi  (b)  apa otun  (d) 

Ipolowo ọ̀ja ni ile yoruba

Pry 3 Akole:ipalowo oja ni ile yoruba Mini a npe ni ipolowo oja? Ipolowo ni ona ti oja ngba ta ni kiakia tan ni kanmo kanmo, tabi niwarasesa,orisirise ona ni a ngba polowo oja awon naa ni awon wonyii 1 ipolowo oja ni ori lkiri 2 ipolowo oja pelu ipate. 3bipolowo oja lori ero ibanisoro.

Yoruba Primary 3 Second Term Examination

2ND TERM EXAMINATION 2012 CLASS: PRIMARY 3   SUBJECT: YORUBA LANGUAGE   NAME:   Comprehension Oko Oluko Oko oluko wa ko sise Awon ore re n ba a ti i Ti awon ore re ba ti I daadaa, Yoo sise kia kia Eje ki a ba a ti I, Ki o le sise kiakia A

Yoruba Second Term Examination Primary 3

NAME:…………………………………………………………………………………… OTITO BORI       Ilu wo ni itan yii ti sele _____ (a) Ayokooto      (b) Ayedande    Kii ni ise Mosun (a) agbejoro     (b) onisowo Talo se ijanba fun Mosun? (a) Agbalagba kan   (b) Omodekunrin kan    Bawo ni won se ko ba Mosun?    (a) won ba Mosun ja        (b) won fi

Èdè Yorùbá : akanlo ede ati itunmo re

  Class: Pry three Subject: Yoruba Studies Akole: akanlo ede ati itunmo re Se aya gbangba! Itumo: ki eniyan doju ko isoro lai beru Ya apa! Itumo: ki eniyan ma mọ itoju owo tabi ohun ti a fi owo ra Edun arinle! Itumo: eni ti o ti lowo ri sugbon ti opa da rago tàbí