YORUBA JSS 3

Mastering Cultural and Creative Arts: Essential Questions for BECE Exam Success

NATIONAL EXAMINATIONS COUNCIL 2024 BASIC EDUCATION CERTIFICATE EXAMINATION CULTURAL AND CREATIVE ARTS 2 hours Please do not open this question booklet until you are told to do so. While waiting, read the following instructions carefully. There are two papers of sixty (60) multiple-choice questions each. Paper I, which is Arts and Crafts, Customs, Traditions, and

JSS 3 FIRST TERM LESSON NOTE YORUBA

ALPHA TERM ILAANA ISE NI SAA KINNI FUN JSS3 YORUBA LANGUAGE OSE AKORI EKO 1 EDE – Atunyewo fonoloji Ede Yoruba iparoje ati isunki ASA – Isinku ni ile Yoruba LITIRESO – Awon Ewi Alohun ti o je mo esin abalaye iyere: ifa, Sango pipe 2 EDE – Aroko Alalaye ASA – Ogun pinpin LITIRESO

JSS 3 YORÙBÁ FIRST TERM LESSON NOTE

  JSS 3 YORUBA LANGUAGE FIRST TERM LESSON NOTES   WEEK 1 ÒǸKÀ LÁTI E̩GBE̩RÚN ME̩WAA TITI DE E̩GBÀÁWÀÁ (10,000-20,000)   WEEK 2 Itoju Alaboyun (1)Igbagbo Yoruba nipa agan, omo bibi ati abiku.   WEEK 3 FONOLOJI EDE YORUBA     WEEK 4 APOLA INU EDE YORUBA     Week 5 EWI AKOMOLEDE    

ATUNYEWO AMI OHUN ATI SILEBU EDE YORUBA

AKORI EKO: ATUNYEWO AMI OHUN ATI SILEBU EDE YORUBA Silebu ni ege oro ti o kere julo ti a le da fi ohun pe ni enu ni ori isemii kan soso. Ege agbaohun (a-gba-ohun) ni silebu je, eyi ni pe iye ibi ti ohun bat i jeyo ninu oro kan ni yoo fi iye silebu

ASA IRANRA – ENI LOWO (COMMUNAL ASSISTANCE)

ASA IRANRA – ENI LOWO (COMMUNAL ASSISTANCE) Asa iranra – eni lowo je ona ti awon Yoruba fi maa n ran ara won lowo ni aye atijo. Asa yii maa n saba jeyo ninu ise oko riro, ile kiko, owo yiya tabi n kan miiran. Asa iranra – eni lowo maa n mu ki ise

ERE IDARAYA

OSE KEFA AKORI EKO: ERE IDARAYA Ere idaraya ni awon ere t tewe – tagba maa n se lati mu ki ara won jipepe. Bi awon Yoruba se feran ise – sise to bee naa ni won ni akoko fun ere idaraya. Akoko ti ise ba dile tabi awon eniyan ba dari bo lati ibi

ATUNYEWO AWON EYA GBOLOHUN

OSE KẸFÀ  AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA GBOLOHUN Gbolohun ni oro tabi akojopo oro ti o ni itumo. Gbolohun le je ipede ti o ni itumo tabi ni ise ti o n se nibikibi ti o ba ti jeyo. Bakan naa a le pe gbolohun ni oro ti a le pin si spola oro-oruko ati

EWI AKOMOLEDE

OSE KÀRÚN  AKORI EKO: EWI AKOMOLEDE JE OLOGBON OMO     A ko mi nifee     Mo mo fee su     A ko mi lror     Mo moro atata I pe     Awon agba lo ko mi ni samusamu     Ti mot i menu ije     Ife mi yato si teni ti n yinmu     Oro