YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS TWO ODUN IGBEKO 2016/2017 YORUBA JSSTWO ISE OOJO FUN SAA KIN-IN-NI Sise atunyewo fonoloji ede Yoruba Atunyewo awon asa ninu ise olodun kin-in-ni Atunyewo awon ewi alohun yoruba Eya gbolohun nipa ise won Asa igbeyawo ni ile Yoruba Kika iwe apileko ti ijoba yan Eya gbolohun Asa
ILANA ISE FUN SAA KETA FUN OLODUN KEJI (JSS TWO) OSE KIN-IN-NI: EDE: ATUNYEWEO ISE SAA KEJI AROKO ALAPEJUWE/ONIROYIN ASA: ATUNYEWO IWA OMOLUABI LITIRESO: ATUNYEWO ISE SAA KEJI: EWI ALOHUN TO JE MO ESIN IBILE BII; IJALA, IYERE IFA, IWI EGUNGUN, abbl OSE KEJI: EDE: LETA GBEFE AWON WO NI A N KO O SI
YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK JSS 2 SISE ATUNYEWO FONOLOJI EDE YORUBA AKOLE ISE EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON EYA GBOLOHUN Gbolohun Ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o. Onka Yoruba (101 – 300) Onka Yoruba (300 – 500) AKAYE OLORO GEERE ASA ISOMOLORUKO IYATO TI O DE BA SIPELI FAWELI Kiko Yoruba
OSE KEWAA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: Kiko Yoruba ni ilana Akoto Ode-Oni Iyato ti o de ba iro konsonati ninu akoto ode-oni Sipele Atijo Sipele Ode Oni Iddo Ido Otta Ota
OSE KESAN-AN EKA ISA:EDE AKOLE ISE: AKOTO Akoto je ona ti a n gba ko sipeli awon oro ede Yoruba sile lona to boju mu lode oni. Sipeli atijo ni ona ti a n gba ko awon oro ede Yoruba sile ki ijobe orile-ede Naijiria to fi owo si ona tuntun ti a le gba
OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKAYE OLORO GEERE Ayoka kika-yoruba fun sekondu olodun meta akeko iwa keji, lati owo ola m. ajuwon etal (2014). Pg43. Itosona- Ka ayoka yii ki o si dahun awon ibeere to tele. Ni asale leyin ti aduke ati iya re je oka ati efo riro tan, iya re
OSE KEJE EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKAYE OLORO GEERE. Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yeni yekeyeke Igbese ayoka kika a.kika ati mimo ohun ti ayoka naa dale lori sise itupale ayoka ni finifinni fifi imo ede, laakaye ati iforabale ka ayoka naa sinu dida
OSE KARUN – UN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: Onka Yoruba (101 – 300) Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Onka ni bi a se n siro nnkan ni ilana Yoruba. Onka Yoruba lati ookanlelogorun-un de eedegbeta ONKA FIGO ONKA NI EDE YORUBA
OSE KERIN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: Gbolohun Ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o. Gbolohun je akojopo oro ti oni oro ise ati ise ti o n je nibikibi ti o ba ti jeyo. Gbolohun Abode/Eleyo oro-ise Eyi ni gbolohun ti ko ni ju oro-ise kan lo. Gbolohun Abode kii gun, gbolohun