OSE KESAN-AN EKA ISA:EDE AKOLE ISE: AKOTO Akoto je ona ti a n gba ko sipeli awon oro ede Yoruba sile lona to boju mu lode oni. Sipeli atijo ni ona ti a n gba ko awon oro ede Yoruba sile ki ijobe orile-ede Naijiria to fi owo si ona tuntun ti a le gba
OSE KEJO EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKAYE OLORO GEERE Ayoka kika-yoruba fun sekondu olodun meta akeko iwa keji, lati owo ola m. ajuwon etal (2014). Pg43. Itosona- Ka ayoka yii ki o si dahun awon ibeere to tele. Ni asale leyin ti aduke ati iya re je oka ati efo riro tan, iya re
OSE KEJE EKA ISE: EDE AKOLE ISE: AKAYE OLORO GEERE. Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yeni yekeyeke Igbese ayoka kika a.kika ati mimo ohun ti ayoka naa dale lori sise itupale ayoka ni finifinni fifi imo ede, laakaye ati iforabale ka ayoka naa sinu dida
OSE KARUN – UN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: Onka Yoruba (101 – 300) Onka Yoruba je ona ti a n gba lati ka nnkan ni ona ti yoo rorun. Onka ni bi a se n siro nnkan ni ilana Yoruba. Onka Yoruba lati ookanlelogorun-un de eedegbeta ONKA FIGO ONKA NI EDE YORUBA
OSE KERIN EKA ISE: EDE AKOLE ISE: Gbolohun Ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o. Gbolohun je akojopo oro ti oni oro ise ati ise ti o n je nibikibi ti o ba ti jeyo. Gbolohun Abode/Eleyo oro-ise Eyi ni gbolohun ti ko ni ju oro-ise kan lo. Gbolohun Abode kii gun, gbolohun
OSE KETA EKA ISE: EDE AKOLE ISE: EYA GBOLOHUN Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re. Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko Gbolohun Onibo asaponle Eyi ni gbolohun ti a fi n se aponle ninu gbolohun nipa lilo oro atoka
OSE KEJI EKA ISE – EDE AKOLE ISE EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON Gbolohun ni afo ti o kun, to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni olori iso. Eya gbolohun nipa ise won Gbolohun alalaye Gbolohun Ibeere Gbolohun ase Gbolohun ebe Gbolohun ayisodi Gbolohun alalaye:Eyi
OSE KIN – IN – NI EKA ISE – EDE AKOLE ISE – SISE ATUNYEWO FONOLOJI EDE YORUBA Fonoloji ni eko nipa eto iro. A le saleye eko nipa eto iro labe awon ori oro wonyi ninu ede Yoruba Iro faweli Iro konsonanti Eto silebu Ohun Ipaje Aranmo Oro ayalo Apetunpe abbl. Atunyewo faweli
Examination Instructions Subject: Basic Technology Time: 1 Hour 30 Minutes Class: JSS 2 Important Notice: Examination malpractices may lead to a repeat of the subject or suspensions. Please do not be involved. Objective Questions The simple medical treatment given to somebody before the arrival of medical personnel is called: (a) Rescue operation (b) First aid