SECOND TERM MID TERM TEST YORUBA ALL CLASSES
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KINNI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyii.
1. kin ni 8 ni onka Yoruba (a) Eejo (b) Eeji
2. Kin ni a n pe omi ni ede geesi? (a) palm oil
(b) water
3. Kini ni a maa n fi omi se ? (a) a maa n muu (b) a maa ge omi
4. O ni o beere (a) Eyin (b) oba
5. A ni ibeere (a) Aja (b) Ewure
6. Kini ni a n pe imu ni ede geesi? (a) nose (b) mouth
7. Kini ni owo ni ede geesi ? (a) hand (b) leg
8. Leta faweleli meloo ni n wa (a) leta faweeli meta (b) leta faweeli meje
9. Alifabeeti ede Yoruba pin si ona ____ (a) meji
(b) mewa
10. Ona meji ti leta alifabeeti ede Yoruba pin si ni_____(a) ohun ati faweeli (b) faweeli ati konsonanti
Kin ni oruko awon aworan wonyii?
11.
(a) moto
(b) Aga
12.
(a) iwe (b) Aso
13.
(a) ese (b) ori
14.
(a) adiye (b) apa
15. (a) Owo (b) eti
IPIN KEJI
A. Ko gbogbo leta alifabeeti Yoruba jade.
B. Ko gbogbo leta faweeli Yoruba jade.
i. _________________________________________
ii. _________________________________________
iii. _________________________________________
iv. _________________________________________
v. ________________________________________
vi. ________________________________________
vii. _______________________________________
SUBJECT: YORUBA CLASS: KILAASI KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyii.
1. Tani a n pe ni alapamasise (a) olopa (b) ole
2. Kin ni ole pati ninu arofo iwa ole ko dara?
(a) ile-eko (b) soosi
3. Kin ni atunbotan oro yi? W + a = (a) wa (b) ga
4. Kin ni A + de = (a) Ede (b) Ade
5. Kin ni a n pe apapo faweeli ati konsonanti? (a) alifabeeti (b) silebu
6. Apapo _____ ni a fi n seda oro (a) gbolohun ati gbolohun (b) konsonanti ati faweeli
7. Ona kan Pataki ti a fin mo afinju ni (a) aso idoti (b) aso mimo
8. Aisan onigbameji ni a mo si (a) kolera (b) eyin riro
9. Ona ti a le fi se itoju ara wa ni (a) wiwe ni osoose (b) wiwe ni ojoojumo
10. Kin ni a n pe aisan iba (a) malaria (b) cough
11. Ta ni Iya Toriola (a) Adepate (b) Bukola
12. Kin ni oruko baba toriola (a) Jemisi
(b) abinuwawaje
13. Kilaasi wo ni Toriola wa? (a) kilaasi keji
(b) kilaasi keta
14. Ise wo ni baba Toriola n se (a) Awako (b) agbe
15. Ijanba wo ni o sele si Toriola? (a) oju re fo
(b) eti re di
IPIN KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi.
a. Ko atunbotan awon oro onisebu wonyi
1. e + ye = __________________
2. o + mi = __________________
3. e + wa = ___________________
4. i + gi = _______________________
5. o + wo = ____________________
B. Kale mo marun -un ninu ohun ti a fi n tun wa se.
Igbale, odo, aga, ada, reeki, omi, tabili, telifisani, ikole
D. Ko leta faweeli marun –un jade
i. __________________________________
ii. __________________________________
iii. _________________________________
iv. ________________________________
v. ___________________________________
SUBJECT: YORUBA CLASS: KETA
Dahun gbogbo awon ibeere wonyii.
1. ____ ni ohun ti ko dara ti ko boju mu ti a ko Gbodo se (a) imototo (b) eewo (d) Alo
2. Fufu jade lati ara (a) agbado (b) ege (d) isu
3. Ounje oloraa ni _____(a) eja (b) iyan (d) gaari
4. Ilana ______ ni alo apamo (a) orin kiko
(b) ibeere ati idahun (d) leta kiko
5. Ta ni o mu ijapa lo si oko ole (a) aja (b) oba
(d) oloko
6. Ta ni o so alo onitan fun Iteola ati Foyinsola
(a) Baba agba (b) iya agba (d) Egbon agba
7. ______ ni ki eeyan moomo se nnkan eewo
(a) Eja dida (b) ase pipa (d) ounje jije
8. _____ko gbodo je eye ega (a) idile olu-oje
(b) idile olufe (d) idile olofa
9. A ko gbodo gbe ewure sepe je eewo. (a) imototo (b) idile (d) ibara –eni-gbe po
10. ______ni alo onitan (a) iroyin (b) apagbe
(d) asamo
11. Ki ni Ijapa fun Erin je (a) eran (b) akara oloyin (d) Oba
12. Lara ogede ni a ti maa n ri ounje wonyi ayafi (a) Booli (b) dodo (d) iresi
13. Iyan je ounje (a) afaralokun (b) doraa (d)amaradan
14. Kin ni ijapa lo ji ninu oko oloko? (a) ila (b) isu (d) ireke
15. Kin ni aja fi si ereke ootun re (a) igba (b) ata (d) eyin
16. Kin ni won fe fi erin je? (a) Ijoye (b) are (d) Oba
17. Kin ni a fi n gun iyan (a) odo (b) pootu (d) baafu
18. Inu ibo ni ijapa re akara naa sii? (a) Inu oyin (b) inu ororo (d) inu epo
19. Tani o ko awon ara ilu ni orin ti won n ko fun erin? (a) Oba (b) Aja (d) Ijapa
20. Meloo nileta faweeli Yoruba (a) leta meje (b) leta marun-un (d) leta meta
IPIN KEJI
Dahun gbogbo ibeere wonyi
A. Daruko ounje Yoruba marun-un
i. _____________________________________
ii. ____________________________________
iii.____________________________________
iv.______________________________________
v. ______________________________________
B. ko awon onka wonyin ni nomba
i. Eejilelogun _______________________
ii. Aarundinlogun __________________________
iii. Ogun ________________________
iv. Eerinlelogun __________________________
5. Aarundinlogbon _______________________
D. Daruko marun-un ninu awon ohun ti a fi n se imototo ayika wa.
i. _____________________________________
ii. ____________________________________
iii.____________________________________
iv.______________________________________
v. ______________________________________
E. Ko leta faweeli yoruba jade
i. _____________________________________
ii. ____________________________________
iii.____________________________________
iv.______________________________________
v. ______________________________________
vi. ______________________________________
vii. _____________________________________
SUBJECT: YORUBA CLASS: KERIN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyiI.
1. Itumo _______ ni akanlo ede maa n ni (a) geere (b) akanda (d) kikun
2. Itumo juba ehoro ni ____(a) fori bale fun ehoro (b) dobale fun ehoro (d) sare lo
3. Kin ni Yoruba n fi owe se (a) ibawi (b) jeun (d) salo
4. _____ ni atewonro (a) Awolowo (b) Orannyan
(d) Oduduwa
5. Ta ni o fi omo re rubo fun odo Esinminrin? (a) Moremi (b) Ogunmola (d) olabisi
6. Akoni obinrin ni _____(a) oduduwa (b) Awolowo (d) moremi
7. Tani o se to eko o fe fun awon omo ile-eko alakoobere ni ipinle iwo orun? (a) Efunroye
(b) Awolowo (d) Oduduwa
8. ____ je asiri ara oto ninu ede Yoruba.
(a) ofo (b) alo (d) owe
9. Ohun ti a roki a to so o ni ____(a) aroso
(b) aroko (d) ajako
10. ___lo gba awon egba sile lowo imunisin oloyoo. (a) Lisabi (b) Awolowo (d) Moremi
11. Omo ilu wo ni Basorun ogunmola (a) Eko
(b) Ibadan (d) Ekiti
12. Kiko ni a maa n ko (a) aroko (b) aroso (d) ajaso
13. Oluko ni ki awon akekoo ______bo lati ile
(a) ko apeko (b) ko aroko (d) so aroso
14. Tani babanla Yoruba? (a) moremi
(b) Obafemi (d) Oduduwa
15. Kini oruko omokunrin kan ti oduduwa bi?
(a) Akindele (b) Okanbi (d) Ejibi
16. Iru eniyan wo ni Bamidele je? (a) Odale
(b) Ore gidi (d) ole
17. Ki lo gbe muyiwa kuro lodo ebi re?
(a) Iwe kika (b) ise sise (d) Igbadun
18. Itumo ilu Oba ni ____(a) ilu oyinbo
(b) ilu ti oba wa (d) ilu oyo
19. Oruko iyawo Bamidele ni (a) Ajike
(b) Arike (d) Atoke
20. Kin ni o sele si Bamidele ni igbeyin?
(a) o ku (b) o salo (d) o sare
21. Ta ni o lo si ilu oba ninu awon ore yi Bamidele/ Muyiwa
22. Aso ise ti kii ya boro ni (a) Buba (b) kijipa
(d) oyala
23. Aso ti obinrin maa n wo bi awotele ni ____
(a) agbeko (b) iro (d) gele
24. Aso olowopooku ni aso ____(a) imurode
(b) leesi (d) aso isere
25. Kin ni a n pe aso ti awon obinrin maa n we sori? (a) ipele (b) fila (d) gele
26. Oruko egbe oloselu ti obafemi Awolowo da sile ni ____(a) Alajeseku (b) Afenifere (d) ogboni
27. Omo ilu wo ni Obafemi Awolowo (a) Ibadan
(b) Eko (d) Ijebu Ikenne
28.Awon ilu wo ni o maa n yo ara ile-ife lenu (a) Egba (b) Igbo (d) Ido
29. Kini oruko omo Moremi (a) oluorogbo (b) kolade (d) olufemi
30. Ilu wo ni Efunroye Tinubu wa tele ri ki o to pada si Abeokuta (a) Ijesa (b) Ijebu (d) Ilu-Ekiti
IPIN KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
A. so itumo awon akanlo ede wonyi.
i. juba ehoro – _______________________
ii. Na papa bora – ___________________________
iii. Fera ku – ________________________________
iv. Foju lounje – ____________________________
v. Oba waja – ______________________________
B. Daruko orisii marun-un ninu awon aso ti okunrin n wo ni ile Yoruba
i. _____________________________________
ii. ____________________________________
iii.____________________________________
iv.______________________________________
v. ______________________________________
D. Daruko marun-un ninu awon akoni Yoruba
i. _____________________________________
ii. ____________________________________
iii.____________________________________
iv.______________________________________
v. ______________________________________
E. Daruko marun-un ninu aso ti awon obinrin n wo ni ile Yoruba
i. _____________________________________
ii. ____________________________________
iii.____________________________________
iv.______________________________________
v. ______________________________________
SUBJECT: YORUBA CLASS: KARUN-UN
Dahun gbogbo awon ibeere wonyiI.
1. Eniyan meloo ni o kopa ninu ayoka onisorogbesi ti a ka (Efunsetan Aniwura) (a)meji (b) meta (d) mewa
2. Ta ni won n soro nipa re ninu ayoka yi (a)osuntunde (b) itawuyi (d) kolade
3. Awon wo ni won fi ija tuka (a) Awero ati itawuyi (b) Adetutu ati Itawuyi (d) Akano ati kike
4. Ta ni ohun re n gbon ninu ayoka yii? (a) Adetutu (b) Bola (d) Awero
5. Orin to wa fun ayeye olokan -o-jokan ni
(a) orin oye (b) orin aro (d) orin ibile
6. Ibi ayeye ti won ko tile e ko orin ibile ni
(a) oku ofo (b) igbeyawo (d) isomoloruko
Nibi ayeye wo ni a ti n gbo awon orin wonyi
7. Iya awa lo
O rorun idera (a) oku agba (b) isile (d) igbeyawo
8. Omo la o fi gbe eee, omo la o fi gbe, owo osun lowo awa je orin (a) ikomojade /isomoloruko (b) ajodun (d) isile
9. O di koro oye naa koole wa (a) igbeyawo (b)odun ibile (d) ayeye oye
10. Awon ti o gbodo fowosi igbeyawo ni ____ (a) alarina (b) obi omo ati molebi (d) iyawo nikan
11. Ewi iyawo fun idagbere ni ___(a) orin iyawo (b) itoro (c) Ekun iyawo
12. Ohun elo idana ni wonyi ayafi (a) isu (b) igi
(d) obi
13. Ewi ti o n dari eto isomoloruko ninu idile ni (a) Baale ile (b) Baba omo (d) iya omo
14. Lara eroja isomoloruko ni wonyi ayafi
(a) atarodo (b) obi (d) oyin
15. Ojo keloo ni a maa n so omo loruko ni ile Yoruba? (a) ojo keta (b) ojo kejo (d) ojo kinni
16. Ba mi na omo mi ___(a) alaigboran ni (b) o ti baje ju (d) ko denu olomo
17. Awon agbateru eto idana laye ode oni ni _______(a) baba oko (b) alaga iduro ati alaga ijoko (d) Baba iyawo
18. Oro ile ti won maa n se fun iyawo lenu ona ile oko re lojo igbeyawo ni _____(a) ese fifo (b) orin kiko (d) owo fifo
19. Ti obinrin ba lahun lati fe oko re ni igba akoko ni a mo si (a) Ijohen/ijohun (b) iya gbo (d) idana
20. Igbese akoko ninu eto igbeyawo ni ____ (a) Ifojusode (b) alarina (d) itoro
Ninu aroso ati aroko ti a menu ba.
21. Akole eko naa ni _____(a) iwe kika (b) aroso ati aroko (d) akaye
22. Oruko oluko yii ni ____(a) ladele (b) olaiye (d) ladeebo
23. Tani o koko dide lati soro lori oro yii (a) Bolanle (b) Tope (d) Sola
24. _____ ni ori oro ti won ko aroko le lori (a)oja ale (b) bi mo se lo isinmi mi (d) ile-iwe mi
25. Iseju meloo ni oluko fun won lati ko aroko yii? (a) mewa (b) ogbon (c) ogoji
26. Odo tani Foyinsola ati Iteola lo lati lo lo isinmi olojo gboro ti o koja (a) Iya ila (b) iya egba (d) iya oyo
27. Ilu wo ni iya ila n gbe (a) ilu oyo (b) ila orangun (d) Eko
28. Ta ni o so itan fun awon Foyinsola ati Iteola? (a) baba won (b) iya won (d) iya ila
29. kin ni oruko omo iya egun? (a) Bose (b) Idowu (d) titi
30. Ta ni iya egun be wi pe ki o ba oun gba owo lowo omo oun? (a) Solomon (b) simoni (d) sidiku
IPIN KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi.
A. Daruko awon ohun eto isomoloruko marun-un
i. __________________________________
ii. __________________________________
iii. _____________________________________
iv. _____________________________________
v. _____________________________________
B. Daruko marun-un ninu igbese ti a gbodo tele ninu eto igbeyawo ni ile Yoruba
i. __________________________________
ii. __________________________________
iii. _____________________________________
iv. _____________________________________
v. _____________________________________
D. Daruko ohun elo idana marun-un
i. __________________________________
ii. __________________________________
iii. _____________________________________
iv. _____________________________________
v. _____________________________________
E. Daruko ibi ayeye marun-un ti a ti lee ko orin ibile
i. __________________________________
ii. __________________________________
iii. _____________________________________
iv. _____________________________________
v. _____________________________________
SUBJECT: YORUBA CLASS: KEFA
Dahun gbogbo awon ibeere wonyiI.
1. Won ki I san _____ pada leyin ise (a) aaro (b) ajo (d) owe
2. Ona ti awon Yoruba n gba se iranlowo fun ara won laye atijo ni (a) asa oge sise (b) asa ikorajo (d) asa iranra-eni-lowo
3. Iranlowo ti a b se fun ana eni lati fi emi imore han je (a) owe ana (b) aaro (d) ajo
4. Aboruboye la n ki (a) Amokoko (b) Babalawo (d) Alaro
5. Oju gbooro la n ki (a) Apeja (b) Alaro (d) Amokoko
6. Aajo ewa ni _____(a) ikini (b) oge sise (d) ilera
7. Oge sise wa fun ____(a) Tokunrin-tobinrin (b)tekuteye (d) tajateran
8. Yato si oge sise ____tun maa n fo idoti oju kuro (a) laali (b) tiroo (d) ara finfin
9. Yiyan ni ____maa n yan oro oruko (a) epon (b) asopo (d) eyan
10. Ise eyan ni lati se ____itumo (a) adinku (b) anikun (d) atokun
11. Eyan asonka ni ____(a) gogoro (b) funfun (d) mefa
12. Ahunya la n ki ____(a) Ahunso (b) alawo (d) ode
13. E ku owo lomi la n ki ____(a) eni to sese bimo (b) eni to sun (d) eni to n se aisan
14. Arepon la n ki _____(a) alagbede (b) alaro (d) agbe
15. Egbe to fese mule daadaa ni egbe ____ (a) alajo (b) olowe (d) alajeseku
16. Osu meloo ni eniyan to le ni anfaani ati ya owu alajeseku? (a) osu meje (b) osu mefa
(d) osu meta
17. Oruko eni to jeolori awon to n da eesu ni olori _____(a) esusu (b) adajo (d) adeesu
18. “Kemi ko ile mewa” Kin ni eyan oro ninu gbolohun yii (a) Kemi (b) mewa (d) ile
19. Alarabara je eyan (a) ajoruko (b) asonka (d) asafihan
20. Ta ni a n pe ni alapamasise (a) ole (b) agbe (d) gbajumo
21. Kin ni 80 ni onka Yoruba (a) ogorun (b) ogota (d) ogorin
22. kin ni 94 ni onka Yoruba (a) Eerinlelaadorun (b) Eerindinlogbon (d) Eerindinlaadorun
23. Iru eyan wo ni a fa ila si yi? Aso funfun ni mowo (a) asapejuwe (b) asonka (d) ajoruko
24. Ohun elo fun alaro ni ____(a) oko (b) aro (d)odo
25. Ohun elo meji Pataki fun awon agbe ni ________ ati ______(a) irin ati afefe (b) omi ati iyo (d) oko ati ada
26. Won le lo agbara ede Yoruba lati se adura nibi _____(a) igbeyawo (b) olejija (d) ijajija
27. Ara oge sise ni ____(a) eti gbigba (b) laali lile (d) ole jija
28. Eyin pipa ni ki _____ wa laarin eyin oke (a) ewa (b) sibi (d) alafo
29. A gbodo maa we ni ___(a) ojoojumo (b) osoose (d) odoodun
30. Kini oro-oruko inu gbolohun yii? Kola sun fonfon. (a) fonfon (b) sun (d) kola
IPIN KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
A. Fa ila si isi eyan oro ninu gbolohun wonyii.
1. epo pupa ni mo fi se obe
2. oro jatijati ni olu so
3. Baba kekere ti de
4. Igbimo yen ni o so be
5. Omo dudu ni Damilare
6. Aso funfun ni kemi wo
7. Ile mewa ni Temiloluwa ko
8. Bisola wo bata gogoro
9. Omi tutu ni mo fi mu gaari
10. Iya agba je amala dudu
B. Daruko ona marun-un ti awon Yoruba n gba ran ara won lowo ni aye atijo
i. ________________________________
ii. _______________________________
iii. _____________________________
iv. ________________________________
v. _________________________________
D. Daruko marun-un ninu ona ti a n gba se oge ni ile Yoruba
i. ________________________________
ii. _______________________________
iii. _____________________________
iv. ________________________________
v. _________________________________
E. Daruko onise marun-un ni ile Yoruba
i. ________________________________
ii. _______________________________
iii. _____________________________
iv. ________________________________
v. _________________________________
E. so ookan ninu ohun elo onise kookan
i. ________________________________
ii. _______________________________
iii. _____________________________
iv. ________________________________
v. _________________________________