YORUBA SECOND TERM EXAMINATION IDANWO TAAMU KEJI SUBJECT: YORUBA CLASS: KEFA
IDANWO TAAMU KEJI
SUBJECT: YORUBA CLASS: KEFA
Dahun gbogbo awon ibeere wonyiI.
- Won ki I san _____ pada leyin ise (a) aaro (b) ajo (d) owe
- Ona ti awon Yoruba n gba se iranlowo fun ara won laye atijo ni (a) asa oge sise (b) asa ikorajo (d) asa iranra-eni-lowo
- Iranlowo ti a b se fun ana eni lati fi emi imore han je (a) owe ana (b) aaro (d) ajo
- Aboruboye la n ki (a) Amokoko (b) Babalawo (d) Alaro
- Oju gbooro la n ki (a) Apeja (b) Alaro (d) Amokoko
- Aajo ewa ni _____(a) ikini (b) oge sise (d) ilera
- Oge sise wa fun ____(a) Tokunrin-tobinrin (b)tekuteye (d) tajateran
- Yato si oge sise ____tun maa n fo idoti oju kuro (a) laali (b) tiroo (d) ara finfin
- Yiyan ni ____maa n yan oro oruko (a) epon (b) asopo (d) eyan
- Ise eyan ni lati se ____itumo (a) adinku (b) anikun (d) atokun
- Eyan asonka ni ____(a) gogoro (b) funfun (d) mefa
- Ahunya la n ki ____(a) Ahunso (b) alawo (d) ode
- E ku owo lomi la n ki ____(a) eni to sese bimo (b) eni to sun (d) eni to n se aisan
- Arepon la n ki _____(a) alagbede (b) alaro (d) agbe
- Egbe to fese mule daadaa ni egbe ____ (a) alajo (b) olowe (d) alajeseku
- Osu meloo ni eniyan to le ni anfaani ati ya owu alajeseku? (a) osu meje (b) osu mefa
(d) osu meta
- Oruko eni to jeolori awon to n da eesu ni olori _____(a) esusu (b) adajo (d) adeesu
- “Kemi ko ile mewa” Kin ni eyan oro ninu gbolohun yii (a) Kemi (b) mewa (d) ile
- Alarabara je eyan (a) ajoruko (b) asonka (d) asafihan
- Ta ni a n pe ni alapamasise (a) ole (b) agbe (d) gbajumo
- Kin ni 80 ni onka Yoruba (a) ogorun (b) ogota (d) ogorin
- kin ni 94 ni onka Yoruba (a) Eerinlelaadorun (b) Eerindinlogbon (d) Eerindinlaadorun
- Iru eyan wo ni a fa ila si yi? Aso funfun ni mowo (a) asapejuwe (b) asonka (d) ajoruko
- Ohun elo fun alaro ni ____(a) oko (b) aro (d)odo
- Ohun elo meji Pataki fun awon agbe ni ________ ati ______(a) irin ati afefe (b) omi ati iyo (d) oko ati ada
- Won le lo agbara ede Yoruba lati se adura nibi _____(a) igbeyawo (b) olejija (d) ijajija
- Ara oge sise ni ____(a) eti gbigba (b) laali lile (d) ole jija
- Eyin pipa ni ki _____ wa laarin eyin oke (a) ewa (b) sibi (d) alafo
- A gbodo maa we ni ___(a) ojoojumo (b) osoose (d) odoodun
- Kini oro-oruko inu gbolohun yii? Kola sun fonfon. (a) fonfon (b) sun (d) kola
IPIN KEJI
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi
A. Fa ila si isi eyan oro ninu gbolohun wonyii.
- epo pupa ni mo fi se obe
- oro jatijati ni olu so
- Baba kekere ti de
- Igbimo yen ni o so be
- Omo dudu ni Damilare
- Aso funfun ni kemi wo
- Ile mewa ni Temiloluwa ko
- Bisola wo bata gogoro
- Omi tutu ni mo fi mu gaari
- Iya agba je amala dudu
B. Daruko ona marun-un ti awon Yoruba n gba ran ara won lowo ni aye atijo
i. ________________________________
ii. _______________________________
iii. _____________________________
iv. ________________________________
v. _________________________________
D. Daruko marun-un ninu ona ti a n gba se oge ni ile Yoruba
i. ________________________________
ii. _______________________________
iii. _____________________________
iv. ________________________________
v. _________________________________
E. Daruko onise marun-un ni ile Yoruba
i. ________________________________
ii. _______________________________
iii. _____________________________
iv. ________________________________
v. _________________________________
E. so ookan ninu ohun elo onise kookan
i. ________________________________
ii. _______________________________
iii. _____________________________
iv. ________________________________
v. _________________________________