Yoruba Language Jss 1 First Term Examinations

Àyọkà ìsalẹ̀ àti Ìbéèrè: Nínú ilé kọọkan ní ilé Yorùbá, ó jẹ́ àṣà pé kí bàbá àti ìyá máa kọ àwọn ọmọ wọn ní ẹ̀kọ́ ìwà hù. Látì kékeré ni iru ẹ̀kọ́ yìí ti ń bẹ̀rẹ̀. Bí ọmọdé bá jí ní ọ̀wúrọ̀, ó ní láti mọ bí a ti ń kí ìyá àti bàbá rẹ̀, … Continue reading Yoruba Language Jss 1 First Term Examinations