NAME: CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: Eko Ede Yoruba Instruction: Answer all the questions OBJECTIVE (30marks) Alifabeeti Ede Yoruba pin si ona melo. (a) meji (b) meta (d) marun _________la
NAME: CLASS: PRIMARY 5 SUBJECT: Eko Ede Yoruba OBJECTIVES Awon iwa ti o boju mu ni a npe ni iwa __________(a) agidi (b) imele (c) omoluabi Ewo ninu awon iwa wonyii ni ko dara? (a) jagidi jagan (b) titepa mose (c) bi bowo fagba Ona ibanisoro laye atijo daraju tode oni. Beeni/ Beeko Asoro
NAME: CLASS: PRIMARY 3 SUBJECT: Eko Ede Yoruba Edahun ibeere yi. O __________ lati maa sere ni opopona. (a) dara (b) buru (c) gbadun _________ ni ibi ti oko maa n gba (a) opopona (b) yara (c) afefe O to lati wo ona daadaa ki a to koja (a) beeni (b) beeko Ibi akoko ti
NAME: CLASS: PRIMARY 4 SUBJECT: Eko Ede Yoruba Ilana: Dahun Gbogbo Ibeere yii Apeere iwaomoluabi ni ________ (a) afojudi (b) ojukokoro (c) ibowofagba Amin ohuna arin ni _________(a) do \ (b) re (c) mi / Amin ohun oke ni __________ (a) re (b) do \ (c) mi / Ewo ninu
NAME: CLASS: Primary 1 SUBJECT: Eko Ede Yoruba E kaaro la ma n so __________ (a) laaro (b) losan (d) ki le Bawo ni a se n kinni losan. (a) E kaaro (b) e kaasan (d) e kaale _________ kii se ona itoju ara eni. (a) wiwe (b) idoti (d) enu fifo Ewo ni
JSS 3 YORUBA LANGUAGE FIRST TERM LESSON NOTES WEEK 1 ÒǸKÀ LÁTI E̩GBE̩RÚN ME̩WAA TITI DE E̩GBÀÁWÀÁ (10,000-20,000) WEEK 2 Itoju Alaboyun (1)Igbagbo Yoruba nipa agan, omo bibi ati abiku. WEEK 3 FONOLOJI EDE YORUBA WEEK 4 APOLA INU EDE YORUBA Week 5 EWI AKOMOLEDE
AKORI EKO: ATUNYEWO AMI OHUN ATI SILEBU EDE YORUBA Silebu ni ege oro ti o kere julo ti a le da fi ohun pe ni enu ni ori isemii kan soso. Ege agbaohun (a-gba-ohun) ni silebu je, eyi ni pe iye ibi ti ohun bat i jeyo ninu oro kan ni yoo fi iye silebu
ASA IRANRA – ENI LOWO (COMMUNAL ASSISTANCE) Asa iranra – eni lowo je ona ti awon Yoruba fi maa n ran ara won lowo ni aye atijo. Asa yii maa n saba jeyo ninu ise oko riro, ile kiko, owo yiya tabi n kan miiran. Asa iranra – eni lowo maa n mu ki ise
OSE KEFA AKORI EKO: ERE IDARAYA Ere idaraya ni awon ere t tewe – tagba maa n se lati mu ki ara won jipepe. Bi awon Yoruba se feran ise – sise to bee naa ni won ni akoko fun ere idaraya. Akoko ti ise ba dile tabi awon eniyan ba dari bo lati ibi
OSE KẸFÀ AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA GBOLOHUN Gbolohun ni oro tabi akojopo oro ti o ni itumo. Gbolohun le je ipede ti o ni itumo tabi ni ise ti o n se nibikibi ti o ba ti jeyo. Bakan naa a le pe gbolohun ni oro ti a le pin si spola oro-oruko ati