CLASS: PRIMARY 1                           SUBJECT: YORUBA NAME:……………………………………………………………………………….. Di awon alafo won yii Ojo __________ ki baba re (a) o duro (b) o dubule (d) o dobale Aina _________ ki iya re. (a) kunle (b) sun (d) joko ___________ ni Ojo wa nigba ti o fun baba re ni ada (a) ijoko (b) iteriba