First Term Primary 4 Examinations Yoruba

Edu Delight Tutors

First Term Primary 4

1st TERM EXAMINATION

CLASS: BASIC 4

SUBJECT: YORUBA

  1. Awon iwa ti obojumu ni anpe ni ………………. [a] agidi [b] imele [c] omoluabi
  2. Ewo ninu awon iwa wonyi ni ko dara……….. [a] jagidijagan [b] siso otito [c]bibowo fagba
  3. Okan lara ona ibara eni soro laye atijo ni…………..
  4. …………… kiise ona ibani soro loode oni. [a] lilo telfonu [b] ilu [c] lilo ero alagbeka
  5. Ona ibanisoro laye atiijo dara ju toode oni lo [a] beeni [b] beeko [c] gbogbo e
  6. ……………. Je ona kan Pataki ti afin saralooge. [a] orun [b] omi mimu [c] ila kiko
  7. Hale tumo si……………….. [a] kia gbiyanju [b] ki apa eniyan [c] ki eniyan saalo
  8. Alifabbeti Yoruba je…………. [a] 18 [b] 24 [c]25
  9. Leeta to paari alifabeeti ede Yoruba ni……………… [a] u [b] y [c] a
  10. Leeta kiko pin si ona ………………… [a] meji [b] kan [c] mejo

Theory

1. Koa won alifabeeti Yoruba.

2. Ko itumo awon akanlo ede wonyii

Tiraka ……………………….

Terigbaso……………………

Hawo……………………………

2b. Ko oruko amutorunwa bi meta ti omo

3a. Koa won fiigo wonyii ni Yoruba;

5=……………………… 10=……………………… 2=……………………

3b. Ko onka wonyi ni figo

Ogun………………. Ogbon………………….. adota………………….

 

(Visited 26 times, 1 visits today)
error: Content is protected !!