2ND TERM EXAMINATION BASIC 1 YORUBA

2ND TERM EXAMINATION

SESSION: .

CLASS: BASIC 1

SUBJECT: YORUBA

 

Fa ila si eyi ti o ye ninu awon oro wonyi: 

 

1. ____se patatki (a) eko-ile (b) eko ode (c) eko adugbo

2. Ni ile Yoruba awon obinrin ma iro afi buba awon okunrin ma de fila dansiki ati Sokoto kenbe (a) beeni (b) beeko (d) boya

3. ______ni onje Ijebu (a) Ikokore (b) Ewedu (d) Mosa

4. ______ni onje Ibadan (a) Amala (b) Fufu (d) koko

5. _____ni o bere alifabeti ede Yoruba (a) k (b) a (d) o

6. ____ni baba nla ile Yoruba (a) Oni-Ife (b) Odudua (d) Olopa

7. Imo toto bori _____mole (a) aarun (b) ewa (d) giri

8. Pat____ko (a) w (b) a (d) o

9. Ikok___(a) k (b) v (d) o

10. Talak___ (a) a (b) t (d) e