Pry 2 Yoruba 1st Term Examinations

FIRST TERM EXAMINATION 2020/2021

CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE

 

Ezoic

NAME:…………………………………………………………………………………

 

ORIN AKOMONIWA: OMO RERE

Ezoic

i.) Omo rere kii ___________ (a) puro (b) sun

ii.) Omo rere kii ___________ (a) kawe (b) sole

iii.) Omo rere kii ___________ (a) seke (b) sise

Ezoic

iv.) Omo rere kii ___________ (a) kole (b) ja

v.) Omo rere kii ___________ (a) jale (b) kiini

 

Ezoic

398385: ITOJU ATI OORE SISE

1.) _______________ nse baba Aina (a) Aisan (b) Aarun

2.) _________________ wa kii. (a) Ojo (b) Aina

Ezoic

3.) Iya ________________ sa awon aso re si ita (a) Ade (b) Yemi

4.) ___________________ nba a ka awon aso naa (a) Bolu (b) Tola

5.) _______________ ati mama re n lo sode (a) Ojo (b) Oke

Ezoic

 

IROYIN ATI ASOGBA

1.) Ile-eko mi dara, talo nsoro yii? (a) Tunde (b) Alaba

Ezoic

2.) Bee ni, sugbon ko dara to ile-eko tiwa? talo lo nsoro yii? (a) Alaba (b) Tunde

3.) Wo o bi ododo se po yi kilaasi mi ka, talo nsoro yii? (a) Alaba (b) Tunde

4.) Wo maluu ti baba mi ra, talo nsoro yii? (a) Tunde (b) Alaba

Ezoic

5.) Ki ni won fe fi se? Talo nsoro yii? (a) Tunde (b) Alaba

 

AROFO IMOTOTO

1.) Fo ______________ re bi o baji (a) eyin (b) ese

2.) Gba __________________ re pelu (a) oju (b) ayika

3.) Ge _______________ re lasiko to ye (a) irun (b) ese

Ezoic

4.) Ge _______________ re to gun sobolo (a) imu (b) eekanna

5.) ______________ abe eekannaa ko kere (a) Arun (b) Aisan

 

Ezoic

 

KIINI AWON LETA WONYI DURO FUN

1.) A = ___________ (a) Aja (b) Obo

Ezoic

2.) B = ___________ (a) Pako (b) Bata

3.) D= ____________ (a) Doje (b) Konga

4.) E = ____________ (a) Omo (b) Ejo

Ezoic

5.) E = ____________ (a) Eye (b) Inaki