YORUBA LANGUAGE PRIMARY 6

PRIMARY
6
SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
NAME:……………………………………………………………………………………
IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON
1.)Omo melo ni baba Dauda bi?
(a) meji (b) meta (d) okan (e) merin
2.)Kini ise awon omo wonyii
(a) agbe (b) ode (d) ademu (e) akekoo
3.)Eranko wo ni a kii je, ti
Dauda maa npa (a) Eye (b) Emo (d) Adan (e) Alangba
4.)Kini o mu ki won re roba Dauda? (a) o fin pa eye (b) o fin pa adan
(d) koje ki o koju si eko re (e)
o fi fo agbe emu
5.)Kini Dauda fi ile agbon pe? (a) ile-eye (b) ile-eku (d) adan (e)
agbe-emu
IWE KIKA: – LAMURIN YA WERE [mediator_tech][mediator_tech]
1.)Iru eniyan wo ni baba
Lamurin (a) oba (b) olowo (d) talaka (e)
ode
2.)Ojo wo ni isele yii waye
ganan (a) ojo ose (b) ojo odun (d) ojo oja (e)
ojo ere
3.)Kini Lamurin lose ni oko ni ojo naa
(a) o lo wa igi (b) o lo he
ekuro (d) o lo sa obi (e) o lo wa isu
4.)Kini o mu inu bi Lamurin
(a) ko gbadun iwe naa(b) o ri
ewu re lorun elomiran(d) omi odo ko kaa
lara(e) orun wo o
5.)Kini awon ero oja fi na
lamurin (a) ada (b) kumo (d) opa (e)
owo
IWE KIKA: – WARA
1.)Awon wo lo nse wara (a)
maluu (b) Fulani (d) bomubomu (e) kolobo
2.)Ni akoko wo ni won maa
nbere ise wara sise (a) osan (b) iyale ta (d) owuro (e) oyanjo
3.)Ara eranko wo ni won ti
nri wara (a) agbo (b) opije (d) ako maluu (e) abo maluu
4.)Iru ewe wo ni won fin se
wara (a) ewe ope (b) ewe odan (d) ewe ibepe (e) ewe bomubomu
5.)Ounje miran ti a maa nsebi wara ni _____ (a) isu (b)
eko (d) oka (e) eba
IKINI LENU ISE ATI IDAHUN
S/N
Onise
Ikini
Idahun
1.)
Alagbede
2.)
Akope
3.)
Babalawo
4.)
Alaro
5.)
Onidiri
6.)
Awako
7.)
Onisowo
8.)
Alayo
9.)
Ode
10.)
Amokoko

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share