PRIMARY 6 YORUBA LANGUAGE

NAME:…………………………………………………………………………………… IWE KIKA: DAUDA JALE AGBON

 

 

  1.    Omo melo ni baba Dauda bi? (a) meji            (b) meta         (d) okan         (e) merin
  2.    Kini ise awon omo wonyii (a) agbe     (b) ode          (d) ademu      (e) akekoo
  3.  Eranko wo ni a kii je, ti Dauda maa npa (a) Eye       (b) Emo          (d) Adan    (e) Alangba
  4.    Kini o mu ki won re roba Dauda? (a) o fin pa eye                (b) o fin pa adan (d) koje ki o koju si eko re       (e) o fi fo agbe emu
  5. Kini Dauda fi ile agbon pe? (a) ile-eye          (b) ile-eku     (d) adan         (e) agbe-emu  

 

 

IWE KIKA: – LAMURIN YA WERE

 

 

  1.    Iru eniyan wo ni baba Lamurin (a) oba          (b) olowo      (d) talaka       (e) ode
  2.    Ojo wo ni isele yii waye ganan (a) ojo ose    (b) ojo odun  (d) ojo oja     (e) ojo ere
  3.   Kini Lamurin lose ni oko ni ojo naa (a) o lo wa igi      (b) o lo he ekuro       (d) o lo sa obi            (e) o lo wa isu
  4.   Kini o mu inu bi Lamurin (a) ko gbadun iwe naa   (b) o ri ewu re lorun elomiran  (d) omi odo ko kaa lara  (e) orun wo o 
  5.    Kini awon ero oja fi na lamurin (a) ada          (b) kumo        (d) opa           (e) owo  

IWE KIKA: – WARA

 

  1. 1.)   Awon wo lo nse wara (a) maluu (b) Fulani (d) bomubomu (e) kolobo
  2.   Ni akoko wo ni won maa nbere ise wara sise (a) osan (b) iyale ta (d) owuro (e) oyanjo  
  3.  Ara eranko wo ni won ti nri wara (a) agbo (b) opije (d) ako maluu (e) abo maluu
  4.   Iru ewe wo ni won fin se wara (a) ewe ope (b) ewe odan (d) ewe ibepe (e) ewe bomubomu
  5.  Ounje miran ti a maa nsebi wara ni _____ (a) isu (b) eko (d) oka (e) eba  

IKINI LENU ISE ATI IDAHUN

S/N Onise Ikini Idahun
1.) Alagbede    
2.) Akope    
3.) Babalawo    
4.) Alaro    
5.) Onidiri    
6.) Awako    
7.) Onisowo    
8.) Alayo    
9.) Ode    
10.) Amokoko    

 

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share

Add a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *