March 30, 2019
SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE
SECOND TERM EXAMINATION 2019 CLASS: PRIMARY 2 SUBJECT: YORUBA LANGUAGE NAME:…………………………………………………………………………………… ERE AYO 1.) ________ ni igi gbooro gidi ti a gbe iho mejila si (a) opon ayo (b) awo ayo 2.) Omo ayo __________ ni o nwa ninu iho Kankan. (a) mejo (b) merin 3.) Apa ___________ ni a nta ayo si (a) otun (b) osi 4.) Enikan _________ ni o nta ayo olopon leekan naa (a) merin (b) meji 5.) Omo ayo ______ ni o ngbe ni oju opon ayo lapapo (a) mejidinladota (b) merinlelogun ALO APAMO 1.) Alo o, alo o, okun nho yaya, osa nho yaya, omo buruku tori bo, kini o (a) irin (b) omorogun 2.) Alo o, alo o, opa tinrin kanle, o karun, kini o (a) ojo (b) agbara 3.) Alo o, alo o, oruku tindin tindin, oruku tindin tindin, oruko bi igba omo, gbogbo won lo le tiro, kini o (a) ata (b) ewa 4.) Alo o, alo o, mo nlo soyo; mo koju soyo, mo nbo loyo, mo koju soyo, kini o (a) ilu (b) igba 5.) Alo o, alo o, aso baba mi kan laelae, aso baba mi kan laelae, eti lo ngbo, kii gbo laarin, kini o (a) agbara (b) odo ALO APAGBE: IJAPA ATI OKERE 1.) _________ ati okere je ore (a) asin (b) ijapa 2.) _______ kii se ore won (a) ijapa (b) asin 3.) Ijapa la ija ___________ (a) ogbon (b) eru 4.) Ija sele laarin ________ ati ______ (a) ijapa ati asin (b) asin ati okere 5.) Inu bii asin gidigidi, o sig e e je ni __________ (a) imu (b) ese IMOTOTO ILE 1.) _______ nge koriko ti o wa ni ayika ile (a) Tunde (b) Kola 2.) _________ ngba idoti ati panti inu ile sita (a) Yemi (b) Bola 3.) Mama ________ sese fo aso tan ni (a) Bola (b) Kemi 4.) Baba ________ naa fe sun panti ti won ti ko jo nina (a) Kola (b) Tunde 5.) O n sa wonsi ori _________ isasosi (a) okun (b) igi
(Visited 34 times, 1 visits today)